OLUWA, y’o ti pe to
Keep this hymn close.
Create an account to keep this hymn in your own hymnbook and return to it anytime.
Read, react and save hymns offline without an account.Verse 1
OLUWA, y’o ti pe to
T’ Iwo o tun pada;
Are fere mu wa tan,
Bi a ti nw’ ona Re;
Oluwa, y’o ti pe to
T’ a o ma reti Re?
Opo ni ko gbagbo mo
Pe ‘Wo o tun pada.
Verse 2
Oluwa y’o ti pe to
T’ Iwo o kesi wa?
Ti awa, ti nreti Re
Yio ri O l’ ayo?
Ji, wundia ti o sun,
Lo kede bibo Re,
Ki gbogbo awon t’ o sun
Le mo pe O mbo wa.
Verse 3
Dide, tan fitila re,
Gbe ewu mimo wo,
Mura lati pade Re,
‘Tori On fere de.
Oluwa, y’o ti pe to
T’ Iwo o tun pada?
Ma je ki are mu wa
Tit’ a o fi ri O.
Keep the words that stay with you.
Save favourite hymns, keep private highlights and bring your reading style back when you sign in.
Read, react and save hymns offline without an account.ConversationA memory, a prayer, a word of encouragement.0 reflections
Every hymn has a story. What is yours?
Share a memory, a prayer or the words that stayed with you. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.