← Back to the hymnbook
Yoruba Baptist Hymns No. 625

SION yara, k’ o je ise giga re

Read. Sing. Share.

Verse 1

SION yara, k’ o je ise giga re,
So f’ aiye pe Olorun ni mole,
Eni to da ‘won orilede ko fe,
K’ enikan segbe s’ inu okunkun.
Je gbogb’ eda gbo ‘yin alafia,
‘Hin rere pe Jesu ti r’ elese pada.

Verse 2

W’ egbegberun ti won sun sinu ese,
B’ a ti de won, sinu tubu ese,
Lai reni so ‘ku Olugbala fun won,
Tab’ iye t’ O fun won ninu ‘ku Re.

Verse 3

Kede f’ enia ati orile-ede,
Pe Ife ni Olorun to da won,
So p’ O re ‘ra re sile lati gb’ eda,
O ku li aiye k’ eda le gb’ orun,

Verse 4

Ran omokunrin nyin ki won j’ ise na,
N’ oro re fun won ni ‘rin ajo won,
S’ adura fun won lat’ okan ki won segun,
Jesu y’o san ohun t’o na pada fun o.

Verse 5

O npada bo, ara Sion k’ O to de,
Je gbogb’ okan mo ‘gbala ore -ofe Re,
Ma je nikan nin’ awon ti O gbala,
S alaipade Re nipa ‘jata re.

Conversation 0 comments

Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.

Share anonymously

No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.

Where are you joining from?

Your city and country appear beside your anonymous comment after review.

Form verification is provided by Cloudflare Turnstile.

Sign in to keep track of replies

Report a lyric correction

Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.

Form verification is provided by Cloudflare Turnstile.Your details are used to respond to this submission.
Support the archive