EFI iyin fun Olorun
EFI iyin fun Olorun, E yin, enyin eda aiye, E yin, eyin eda orun. Yin Baba, Omo on Emi.
Read hymn : EFI iyin fun OlorunEFI iyin fun Olorun, E yin, enyin eda aiye, E yin, eyin eda orun. Yin Baba, Omo on Emi.
Read hymn : EFI iyin fun OlorunmJE k’ agb’ oju ayo s’ oke Si agbala orun, K’ a yo lati ri Baba wa Lori ite ife.
Read hymn : mJE k’ agb’ oju ayo s’ okeEYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo.
Read hymn : EYO gbogb’ orile-edeOWO at’ Alabukunfun Ni ile t’ o jewo Jesu, Okan at’ ile na l’ ayo Nibiti Olugbala wo.
Read hymn : OWO at’ AlabukunfunNIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun.
Read hymn : NIWAJU ‘te Jehofa nlaE Yin Oluwa, e tun ohun se, Lati korin Re ninu ajo nla; E je k’ aiye yo ninu Eleda won, K’ akobi igbala yo n nu Oba won.
Read hymn : E Yin Oluwa, e tun ohun seDIDUN n’ ise na, Oba mi, Lati ma yin oruko Re, Lati se ‘fe Re l’ owuro, Lati so-oro Re l’ale.
Read hymn : DIDUN n’ ise na, Oba miEWOLE f’ Oba, ologo julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni, at’ Eni Igbani, O ngbe ‘nu ogo, eleru ni iyin.
Read hymn : EWOLE f’ Oba, ologo juloYin, enyin iji t’ o dide N’ igboran s’ ase Re K’ oke at’ igi eleso Dapo yin Oluwa.
Read hymn : YIN Oluwa, oro didunOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin.
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funYIN Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l’ oke K’ orun at’ osupa ko, K’ awon ‘rawo f’ iyin fun.
Read hymn : YIN Oluwa, orun woleIRANSE, e fonrere Oba nyin, E si tan ‘hin oruko nla Re ka, Gbe oruko Asegun ti Jesu ga, Ijoba Re l’ ogo, o ka gbogb’ aiye.
Read hymn : IRANSE, e fonrere Oba nyin