EFI iyin fun Olorun
EFI iyin fun Olorun, E yin, enyin eda aiye, E yin, eyin eda orun. Yin Baba, Omo on Emi.
Read hymn : EFI iyin fun OlorunEFI iyin fun Olorun, E yin, enyin eda aiye, E yin, eyin eda orun. Yin Baba, Omo on Emi.
Read hymn : EFI iyin fun OlorunmJE k’ agb’ oju ayo s’ oke Si agbala orun, K’ a yo lati ri Baba wa Lori ite ife.
Read hymn : mJE k’ agb’ oju ayo s’ okeEYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo.
Read hymn : EYO gbogb’ orile-edeOWO at’ Alabukunfun Ni ile t’ o jewo Jesu, Okan at’ ile na l’ ayo Nibiti Olugbala wo.
Read hymn : OWO at’ AlabukunfunNIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun.
Read hymn : NIWAJU ‘te Jehofa nlaE Yin Oluwa, e tun ohun se, Lati korin Re ninu ajo nla; E je k’ aiye yo ninu Eleda won, K’ akobi igbala yo n nu Oba won.
Read hymn : E Yin Oluwa, e tun ohun seDIDUN n’ ise na, Oba mi, Lati ma yin oruko Re, Lati se ‘fe Re l’ owuro, Lati so-oro Re l’ale.
Read hymn : DIDUN n’ ise na, Oba miEWOLE f’ Oba, ologo julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni, at’ Eni Igbani, O ngbe ‘nu ogo, eleru ni iyin.
Read hymn : EWOLE f’ Oba, ologo juloYin, enyin iji t’ o dide N’ igboran s’ ase Re K’ oke at’ igi eleso Dapo yin Oluwa.
Read hymn : YIN Oluwa, oro didunOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin.
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funYIN Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l’ oke K’ orun at’ osupa ko, K’ awon ‘rawo f’ iyin fun.
Read hymn : YIN Oluwa, orun woleIRANSE, e fonrere Oba nyin, E si tan ‘hin oruko nla Re ka, Gbe oruko Asegun ti Jesu ga, Ijoba Re l’ ogo, o ka gbogb’ aiye.
Read hymn : IRANSE, e fonrere Oba nyinGBOGBO eda dapo, E jo yin Oluwa, E pa ohun nyin po Lati fe oro na;
Read hymn : GBOGBO eda dapoGBOGBO eda labe orun. E fi iyin fun Eleda wa: Ki gbogbo orile-ede Ko Olugbala wa l’ orin.
Read hymn : GBOGBO eda labe orunDIDE, yin Oluwa, Enyin, ayanfe Re; E f’ okan ati ohun yin, N’ iduro, yin l’ ogo.
Read hymn : DIDE, yin OluwaENYIN iran Adam, Da ohun orin po, Mo t’ orun at’ aiye, Lati yin Eleda;
Read hymn : ENYIN iran AdamBABA wa ti o mbe l’ orun, Owo l’ oruko Re, ‘Joba Re de, ife Re ni K’ a se bi ti orun.
Read hymn : BABA wa ti o mbe l’ orunWA rohin Re yika K’o si korin ogo; Alagbara ni Oluwa Oba gbogbo aiye.
Read hymn : WA rohin Re yikaOLUWA t’ o mo julo, K’ a wole l’ oruko Re; Ife Re ki ye titi, Kab’yesi Oba rere.
Read hymn : OLUWA t’ o mo juloKO mi Oluwa bi a ti Je gbohungbo oro Re; B’ O ti wa mi je k’ emi wa, Awon omo Re t’ o ti nu.
Read hymn : KO mi Oluwa bi a tiOLUWA, a wa ‘do, Re, L’ese Re l’ a kunle si; A! ma kegan ebe wa, A o wa O lasan bi?
Read hymn : OLUWA, a wa ‘do, Re,JESU, nib’ eni Re pade, Nibe nwon r’ ite anu Re; Nibe nwon wa O, nwon ri O, Ibikibi n’ ile owo.
Read hymn : JESU, nib’ eni Re padeMO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajeji, Ile mi jin rere, l’or’ ebute wura; Lati je iranse n’koja okun l’ohun, Mo nsise nihin f’ oba mi
Read hymn : MO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajejiGBAT’ okan are fe ‘simi, T’ o nwa Olorun re, B’ o ti dun to lati r’ ale T’ o pin ose lala.
Read hymn : GBAT’ okan are fe ‘simi