A BAPTIS’ wa sinu iku
A BAPTIS’ wa sinu iku, Nipa itebo ‘mi; A sin wa ‘nu ‘boji Jesu, A sin wa pelu Re.
Read hymn : A BAPTIS’ wa sinu iku643 hymns
A BAPTIS’ wa sinu iku, Nipa itebo ‘mi; A sin wa ‘nu ‘boji Jesu, A sin wa pelu Re.
Read hymn : A BAPTIS’ wa sinu ikuA F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun:
Read hymn : A F’ iyin aiku funA F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo;
Read hymn : A F’ ope f’ OlorunA IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si.
Read hymn : A IGBAGBO bila! T’ emi l’ OluwaA JESU, Iwo nduro Lode, lehin ‘lekun, Iwo fi suru duro Lati koja s’ ile;
Read hymn : A JESU, Iwo nduroA JIN jin, oru mimo, Okun su, mole de, Awon olus’ agutan nsona, Omo t’o wa l’ oju orun,
Read hymn : A JIN jin, oru mimoA KO ni ‘bugbe kan nihin, Onile e roar yanran; B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet, Ese mefa ni busun wa.
Read hymn : A KO ni ‘bugbe kan nihinA NT’ ona t’ Oluwa war in: A ngb’ agbelebu Re; Gbogb’ egun t’o ngun wa l’ese Ti gun l’ori saju.
Read hymn : A NT’ ona t’ Oluwa war inA RA, e wa ba mi s’ ofo, E wa sodo Olugbala; Wa, e je k’ a jumo s’ ofo; A kan Jesu m’ agbelebu.
Read hymn : A RA, e wa ba mi s’ ofoA RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu nikan.
Read hymn : A RE mu o okan re poruruA WON eye n’ ife, Kolokolo n’ iho, enia n’ ile: Eda n’ ib’ isimi Sugbon Jesu ko r’ ibi gborile.
Read hymn : A WON eye n’ ife“A YE si mbe!” ile Odagutan, Ewa ogo re npe o pe, “Ma bo”, Wole, wole, wole nisisiyi.
Read hymn : A YE si mbe!” ile Odagutan