ENYIN ti nkoja
ENYIN ti nkoja Ya sodo Jesu: O s’ asan fun nyin bi, bi Jesu ba ku?
Read hymn : ENYIN ti nkojaENYIN ti nkoja Ya sodo Jesu: O s’ asan fun nyin bi, bi Jesu ba ku?
Read hymn : ENYIN ti nkojaMO f’ ara Mi fun o, Mo ku nitori re, Ki nle ra o pada, K’ o le jinde n’nu ‘ oku;
Read hymn : MO f’ ara Mi fun oA RA, e wa ba mi s’ ofo, E wa sodo Olugbala; Wa, e je k’ a jumo s’ ofo; A kan Jesu m’ agbelebu.
Read hymn : A RA, e wa ba mi s’ ofoEGB’ ohun ife at’ anu, Ti ndun l’ oke Kalfari! Wo! O san awon apata! O mi ‘le, o m’ orun su!
Read hymn : EGB’ ohun ife at’ anuOLUGBALA mi ha gb’ ogbe? K’ Oba Ogo si ku? On ha je f’ ara Re rubo F’ eni ile b’ emi?
Read hymn : OLUGBALA mi ha gb’ ogbeAGBELEBU ni ere mi, Nibe ni a rubo fun mi; Nibe l’ a kan Oluwa mo Nibe l’ Olugbala mi ku.
Read hymn : AGBELEBU ni ere miGBO-GB’ ogo iyin ola, Fun O oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun!
Read hymn : GBO-GB’ ogo iyin olaWO t’ o nbebe f’ ota Re, L’ or’ igi agbelebu; Wipe “Fiji won Baba”, Jesu sanu fun wa.
Read hymn : WO t’ o nbebe f’ ota ReMA gesin lo l’ olanla Re; Gbo, gbogb’ aiye nke “Hosanna”, Olugbala ma lo pele Lori ‘m’ ope at aso.
Read hymn : MA gesin lo l’ olanla ReKRIST’ Oluwa ji loni, – Halleluyah, Eda at’ Angeli nwi – Hal. Gb’ ayo at’ isegun ga – Hal. K’ orun at’ aiye gberin! – Hal.
Read hymn : KRIST’ Oluwa ji loni, – HalleluyahOku! – Ore elese ku Omobirin Salem’ Sokun; Okunkun bo oju orun, Ile wariri lojiji.
Read hymn : Oku! – Ore elese kuORUN, korin! Aiye, yo! Angeli at’ enia, E yi ka b’ O ti ndide, E gbe ‘yin Jesu nyin ga.
Read hymn : ORUN, korin! Aiye, yo