EGB’ ohun ife at’ anu
EGB’ ohun ife at’ anu, Ti ndun l’ oke Kalfari! Wo! O san awon apata! O mi ‘le, o m’ orun su!
Read hymn : EGB’ ohun ife at’ anu643 hymns
EGB’ ohun ife at’ anu, Ti ndun l’ oke Kalfari! Wo! O san awon apata! O mi ‘le, o m’ orun su!
Read hymn : EGB’ ohun ife at’ anuEJE k’ a f’ inu didun, Yin Oluwa Olore; Anu Re, o wa titi, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : EJE k’ a f’ inu didunEJERI, angel’ enia Niwaju Oluwa, On l’ awa mba da majemu, T’ a ko gbodo baje.
Read hymn : EJERI, angel’ eniaEKUN ko le gba mi, Bi mo le f’ekun we ‘ju; Ko le mu eru mi tan, Ko le we ese mi nu;
Read hymn : EKUN ko le gba miELESE e yi pada, Ese ti e o fi ku? Eleda nyin ni nbere; T’ O fe ki e ba On gbe:
Read hymn : ELESE e yi padaELESE kil’ o ni t’ o Jo ayo onigbagbo? Pelu ododo riro, Ona re dun to ti ‘wa
Read hymn : ELESE kil’ o ni t’ oELESE wa sodo Jesu Enit’ O wa gba o la Enit’ O gbe are re wo, Lati irora re.
Read hymn : ELESE wa sodo JesuELESE, nipa ‘jewo re Si itiju Jesu, Si irora at’ iku Re Lori agbelebu.
Read hymn : ELESE, nipa ‘jewo reELESE, o ha gan ise T’ a f’ anu ran lat’ oke Ohun jeje l’ O fi ranse, Oro Re kun fun ife;
Read hymn : ELESE, o ha gan iseELESE; – mo nfe ‘bukun; Onde; – mo nfe d’ omnira; Alare; – mo nfe ‘simi; “Olorun sanu fun mi.”
Read hymn : ELESE; – mo nfe ‘bukunEMA te siwaju, Kristian ologun, Ma tejumo Jesu t’ O mbe niwaju Kristi Oluwa wa ni Balogun wa, Wo! asia Re wa niwaju ogun;
Read hymn : EMA te siwaju, Kristian ologunEMI anu, oto, ife, Ran agbara Re t’ oke wa; Mu iyanu ojo oni, De opin akoko gbogbo.
Read hymn : EMI anu, oto, ife