ISE re Oluwa
ISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re. O ri ailera mi, Aisan at’ aigbadun Irora mi losan loru, Orun ko
Read hymn : ISE re Oluwa643 hymns
ISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re. O ri ailera mi, Aisan at’ aigbadun Irora mi losan loru, Orun ko
Read hymn : ISE re OluwaISE ‘gbala pari, Jesu ti ba ‘ku ja, O se agbara iboji, O ti di asegun. Ileri t’O ti se, F’awon omo ehin Re, Bi Olorun Alagbara, O f’otito r
Read hymn : ISE ‘gbala pariISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi, Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de; Simi okan mi, eyikeyi t’ o de, O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya. Ko to
Read hymn : ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yiISIN l’ o le fun wa li Ayo didun li aiye; Isin ni yio fun wa li Itunu nigba ba ku. Lehin ‘ku ayo re y’o Wa titi aiyeraiye; Ki Olorun j’ ore
Read hymn : ISIN l’ o le fun wa liISUN kan wa t’o kun f’eje O yo n’iha jesu, Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. ‘Gba mo f’igbagbo r’isun na, Ti nsan fun ogbe Re, Irapada d’
Read hymn : ISUN kan wa t’o kun f’ejeITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan si, Itan iyanu t’ ife! Ti dun l’eti kikan! Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo Elese iwo ki yio gb
Read hymn : ITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan siITAN kan wa f’ awon orile, Ti yio tun okan won se, Itan otito ti o si dun, Itan alafia on ‘mole, Itan alafia on ‘mole, Tori okunkun yio di
Read hymn : ITAN kan wa f’ awon orileITANA t’ o bo ‘gbe l’ aso, T’o tutu yoyo be; Gba doje ba kan, a si ku, A subu, a siro. Apere yi ye f’ ara wa, B’ or’ Olorun ti wi; K’ omode
Read hymn : ITANA t’ o bo ‘gbe l’ asoITE anu! E je k’a lo Lati gba adura; Olorun ‘fe y’o sanu fun Awon t’o nsin nibe. Ite anu! A, n’ite ns L’ekun wa ti nkunle; Olorun si nro ‘j
Read hymn : ITE anu! E je k’a loIWE kan wa ti kika ra, Ko soro fun enia, Ogbon ti awon t’o ka nfe, Ni okan ti o mo. Ise gbogbo t’Olorun se L’oke n’ile n’nu wa; Nwon j’okan
Read hymn : IWE kan wa ti kika raIWO ha nberu p’ ota yio segun? Okun su lode o sis u ju ninu? Si ferese ati ilekun sile, Jeki ‘ran orun wole. Jeki ‘ran orun wole. Jeki ‘ran
Read hymn : IWO ha nberu p’ ota yio segunIWO imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O Kuro l’ oju iranse Re. Nigbat’ orun ale didun Ba npa ipenpeju mi de, K’ ero mi
Read hymn : IWO imole okan miIWO low’ Enit’ ire nsan, Mo gb’ okan mi si O; N’ ibanuje at’ ise mi, Oluwa ranti mi. ‘Gba mo kerora l’ okan mi, Ese wo mi l’ orun; Dari gbo
Read hymn : IWO low’ Enit’ ire nsanIWO Oro Olorun, Ogbon at’ oke wa, Oto ti ki ‘yipada, Imole aiye wa; Awa yin O fun ‘mole, T’ inu iwe mimo; Fitila fun ese wa, Ti ntan titi ai
Read hymn : IWO Oro OlorunIWO oro t’o tobi, Ninu eyit ‘a ri, Ileri ati sise Awamaridi ni: Nigba ekun at’ ayo, Idanwo at’ eru, Mo gbo Jesu wipe, “Wa” Mo si lo sodo Re.
Read hymn : IWO oro t’o tobiIWO ti gbogbo eda nsin L’ ara erupe yi, Bi O tit obi to l’aiye! B’ ogo Re ti po to! Nigbati mo f’ iyanu wo Ogo ‘se Re l’ oke, Osupa ti njob
Read hymn : IWO ti gbogbo eda nsinIWO ti okunkun Gb’ oro agbara Re, T’ o si fo lo; Gbo ti wa, a mbe O, Nibit’ ihinrere, Ko ti tan ‘mole re, K’ imole wa. ‘Wo t’ iye apa Re Mu
Read hymn : IWO ti okunkunIYE wa ni wiwo, Enit a kan mo ‘gi Iye wa nisisiyi fun o; Nje wo O elese k’ o le ri igbala, Wo Enit’ a kan mo ‘gi fun o. Wo! wo! wo k’ o ye,
Read hymn : IYE wa ni wiwo, Enit a kan mo ‘giJE ni imole ojo Para kuro loju mi, Lala mi rekoja lo, Ngo ba Oluwa soro. ‘Wo t’ oju Re ri yika, Oba arinu r’ode, Dari gbogbo ese ji, T’ iko
Read hymn : JE ni imole ojoJE ran orun kekere nibiti o nlo, Se ranlowo lati le okunkun l’ aiye, ‘Wo o ri b’ okunkun yio ti lo kuro, B’ iwo ba je ‘mole njojumo. Je mol
Read hymn : JE ran orun kekere nibiti o nloJE, Oluwa, sin wa jeje, L’ aiye omije yi ja, Si fun wa l’ ore-ofe Re Ninu eru wa gbogbo: Tu wa ninu Larin aginju aiye. Gba ‘damu nta ‘fa yi
Read hymn : JE, Oluwa, sin wa jejeJEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re; B’ o si ti ngoke pele, Je l’ agbara re npo, Titi y’o fi ka
Read hymn : JEJE, lai si ariwoJEKI m’ n’ ipo mi lodo Re, Jesu, Iwo isimi mi; ‘Gbana l’ okan mi y’o simi Y’o si ri ekun ‘bukun gba. Jeki m’ n’ ipo mi lodo Re, K’ emi k’ o
Read hymn : JEKI m’ n’ ipo mi lodo ReJEK’ alore Sion dide Gba ipe fun ‘ra won; Jeki nwon gba ase wuwo Lat’ enu Oluwa. Ki ‘se ise kekere ni A nfe oluso si; O to kun angeli l’ ok
Read hymn : JEK’ alore Sion dide