GBO ‘gbe ayo! Oluwa de
GBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin O de lati t’ onde sile, L’ oko eru Esu; ‘Lekun ‘de
Read hymn : GBO ‘gbe ayo! Oluwa de643 hymns
GBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin O de lati t’ onde sile, L’ oko eru Esu; ‘Lekun ‘de
Read hymn : GBO ‘gbe ayo! Oluwa deGBO! Orin ti Jubili, O dabi sisan ara; Tabi bi kikun okun, Gbat’ igbi re ba nlu ‘le Halleluya! Olorun Olodumare joba; Halleluya! K’ oro na D
Read hymn : GBO! Orin ti JubiliGBO-GB’ ogo iyin ola, Fun O oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun! ‘Wo l’ Oba Israeli, Om’ Alade Dafidi, T’ O wa l’ Oko Oluwa, Oba
Read hymn : GBO-GB’ ogo iyin olaGBOGBO aiye, gbe jesu ga, Angeli’, e wole fun: E mu ade Oba Re wa, Se l’Oba awon oba. E se l’Oba, enyin Martir’ Ti nkepe n’ ite Re; Gbe gbo
Read hymn : GBOGBO aiye, gbe jesu gaGBOGBO eda dapo, E jo yin Oluwa, E pa ohun nyin po Lati fe oro na; K’ ife da orin open la, Ki gbogbo eda k’ o si gbe. Sugbon o ye k’ iyin T
Read hymn : GBOGBO eda dapoGBOGBO eda labe orun. E fi iyin fun Eleda wa: Ki gbogbo orile-ede Ko Olugbala wa l’ orin. Titi l’ anu Re, Oluwa. Oto Re si duro lailai Iyin
Read hymn : GBOGBO eda labe orunGBOGBO eje eran, Ti pepe awon ju, Ko le f’ okan l’ Alafia, Ko le we eri nu. Kristi Od’-agutan, M’ ese wa gbogbo lo; Ebo t’ o ni oruko nla,
Read hymn : GBOGBO eje eranGBOGB’ ogun orun nro keke, Angeli mu harpu won, Awon mimo nt’ ohun won se Lati josin t’ o l’ ogo; Ojo ‘simi t’ Olorun de, Ojo t’ o l’ ogo ju
Read hymn : GBOGB’ ogun orun nro kekeGB’ adura wa Oluwa, F’ awon omo t’ O fun wa, Pin wa ninu ‘bukun Re, Si fun won l’ ayo l’ orun. Je k’ okan won sunmo O, Nigba won wa l’ omod
Read hymn : GB’ adura wa OluwaGB’ ohun to t’ orun wa ti wi, Bukun f’ oku onigbagbo Nwon bo ninu lala aiye Aiye ki yio tun mo won mo, Ma sokun mo, Ma sokun mo, Onigbagbo m
Read hymn : GB’ ohun to t’ orun wa ti wiGB’ ohun t’ o orun wa ti wi F’ awon mimo t’ o ku, “Didun l’ orun oruko won, ‘Busun won n’ itura.” “Nwon ku n’nu Jesu, orun won Si kun fun i
Read hymn : GB’ ohun t’ o orun wa ti wiGB’ ope mi, Oluwa, Lat’ okan l’ o ti wa, Iwo t’ O gba die opo, K’yo kegan ‘more mi. Tire ‘ eran gbogbo, Ti nfo lori oke; Gbogbo ‘sura t’ o
Read hymn : GB’ ope mi, OluwaGB’ opo duru pelu ohun Nwon nkorin iyin loke; Jesu joba, orun si yo; Olorun ife joba; Wo, O joko lori ite; Jesu nikan job’aiye. Jesu, ‘wo t
Read hymn : GB’ opo duru pelu ohunGB’ ori soke alare, Tori ayo nbo l’ owuro, Olorun so n’nu oro Re Pe ayo ma nbo l’ owuro, Ayo ma nbo l’ owuro, Ayo ma nbo l’ owuro, Ekun le
Read hymn : GB’ ori soke alareHA! egbe mi, e w’ asia Bi ti nfe lele Ogun Jesu fee de na, A fere segun! “D’ odi mu, emi fere de,” Beni Jesu nwi, Ran ‘dahun pada s’ orun pe
Read hymn : HA! egbe mi, e w’ asiaHALLELUYAH, Halleluyah, E gbe ohun ayo ga, E korin inudidun, K’ e si yin olorun wa, Enit’a kan m’agbelebu, T’ o jiya fun ese wa; Jesu Kristi
Read hymn : HALLELUYAH, HalleluyahIBU ife! O le je Pe a p’anu mo fun mi; Olorun mi ha le da ‘Binu ro fun elese? Mo ti mb anu ja tip e! Mo ti nbi n’inu tip e! Mo di ‘ti si if
Read hymn : IBU ife! O le jeIBUKUN ni f’ oku, T’ o simi le Jesu; Awon t’ o gb’ ori won Le okan aiya Re. Iran ‘bukun l’ eyi, Kosi boju larin; Nwon ri En’ Imole, Jesu Ol
Read hymn : IBUKUN ni f’ okuIFE lo to bayi? Ohun gbogbo pari, O ti pari gbogbo ise T’ O tori re w’ aiye. Ohun ti Baba fe, Ni Jesu ti se tan; Wahala ati iya Re, Ni Bibe
Read hymn : IFE lo to bayiIFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun. Iku at’ ayida nsise; Enia nbaje, aiye nlo, S
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro. Mo r’ enikan nro lor’ igi, N’ irora on eje, O te oju are
Read hymn : IFE mi s’ ibi ti wa peIFE orun alailegbe, Ayo orun sokale: Fi okan wa se ‘bugbe Re, Se asetan anu Re; Jesu, iwo ni alanu, Iwo l’onibu ife, Figbala Re be wa wo, M’
Read hymn : IFE orun alailegbeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa. B’ ona ajo wa tile gun, T’ ibanuje kun o
Read hymn : IFE orun t’ o teribaIFE orun! alailegbe! N’nu ase mimo yi, Ogo re kun, ‘mole re po, Ti ntan iye jade. Iku on eje ‘yebiye, T’ a ta sile fun wa Fun ‘wenum’ okan
Read hymn : IFE orun! alailegbe