ESE ti e ko le sailo
ESE ti e ko le sailo Emi nyin danu lor’ asan, Ti ohun kanso, na t’ o ye, Ko si n’nu gbogbo ero nyin? Olorun npe lat’ oke wa, Jesu nfi ‘fe i
Read hymn : ESE ti e ko le sailo643 hymns
ESE ti e ko le sailo Emi nyin danu lor’ asan, Ti ohun kanso, na t’ o ye, Ko si n’nu gbogbo ero nyin? Olorun npe lat’ oke wa, Jesu nfi ‘fe i
Read hymn : ESE ti e ko le sailoETUN won ko fun mi ki ngbo Oro ‘yanu t’ Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro ‘yanu t’ Iye, Oro iye at’ ewa, ti mko mi n’ igbagbo! Oro didun! O
Read hymn : ETUN won ko fun mi ki ngboEWA otosi elese, Wa li akoko anu; Jesu nduro lati gba nyin, O kun fun ‘fe at’ ipa; O le gba nyin, O fe, ma siyemeji. Ma je k’ ero da nyin d
Read hymn : EWA otosi eleseEWE ti Oba orun, Korin didun b’ e ti nlo; Korin ‘yin t’ Olugbala, Ise Enit’ o l’ ogo. E nlo sodo Olorun, L’ ona t’ awon baba nrin, Nwon si
Read hymn : EWE ti Oba orunEWOLE f’ Oba, ologo julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni, at’ Eni Igbani, O ngbe ‘nu ogo, eleru ni iyin. E so t’ ipa Re, e so t’ ore R
Read hymn : EWOLE f’ Oba, ologo juloEYI l’ ojo Oluwa da, O pe ‘gba na n Tire; K’ orun ko yo, k’ aiye k’ o yo, K’ iyin y’ ite na ka. Loni, O jinde n’nu oku, Ijoba Satan’ tu; ‘W
Read hymn : EYI l’ ojo Oluwa daEYI, e yipada, ese t’ e o ku, Nigbat’ Olorun sunmo wa li anu? Jesu npe nyin, Emi sin wipe k’ e wa, Angeli si nduro lati mu nyin lo. Asan ni
Read hymn : EYI, e yipada, ese t’ e o kuEYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo. Oluwa On ni Olorun, T’ O fun wa ni gbogbo ebun
Read hymn : EYO gbogb’ orile-edeEYO Jesu joba N’nu omo enia, O da ara tubu, O so won d’omnira: K’esu koju s’Om’Olorun Lai f’ota pe, ise Re nlo. Ise ti ododo, Oto Alafia, F
Read hymn : EYO Jesu jobaEYO, eyin mimo, e yin Ibukun; anu, igbala, Jesu oke nyin titi lai, D’ oju ko agbara iji. Abo lowolowo ni se, Ife Re to b’ oke giga; Apata l
Read hymn : EYO, eyin mimo, e yinFI ibukun Re tu wa ka, Fi ayo kun okan wa; K’ olukuluku mo ‘fe Re, K’ a l’ ayo n’ nu ore Re, Tu wa lara, tu wa lara La aginju aiye ja. Ope
Read hymn : FI ibukun Re tu wa kaFUN aanu t’ o po b’ iyanrin, Ti mo ngba lojojo Lat’ odo Jesu Oluwa, Kili emi le tun? Kili ohun ti mo le fun un Lat’ inu okan mi? Ese ti ba
Read hymn : FUN aanu t’ o po b’ iyanrinFUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi; Irele on suru At’ opo oiyonu, Ninu ohun gbogbo Ki njo Jesu. Fun mi n’ itelorun N’
Read hymn : FUN mi n’ iwa peleFUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘re Funrugbin l’ osan gan, ati ni ale Duro de ikore ati ‘gba ikojo A o f’ ayo pada, ru iti wole. Ru iti wo
Read hymn : FUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘reFUNRUGBIN l’ owuro, Ma simi tit’ ale; F’ eru on ‘yemeji sile Ma fon s’ ibi gbogbo. ‘Wo ko mo ‘yi ti nhu, T’ oro tabi t’ ale; Ore ofe yio pa
Read hymn : FUNRUGBIN l’ owuroF’ AWON enia Re t’ o lo ‘smi Awon ti o f’ igbagbo jewo Re, Ki yin oruko Re, Olugbala, Alleluya! Iwo l’ apata won at’ odi won, Iwo ni Balogu
Read hymn : F’ AWON enia Re t’ o lo ‘smiF’ ERU re f’ afefe, N’ ireti, ma foya, Olorun gbo ‘mikanle re, Yiop gb’ ori re ga. N’ irumi at’ iji, Yio s’ ona re fefe, Duro de igba re; o
Read hymn : F’ ERU re f’ afefeF’ ORUK’ Olorun loke, T’ O l’ agbara at’ ola, Olorun ibi gbogbo, N’ iyin ati ogo wa. F’ oruko Krist’ Oluwa, Om’ Olorun ti a bi, Krist’ t’ O
Read hymn : F’ ORUK’ Olorun lokeF’ORUKO Jesu s’ okan re Om’ egbe on ‘banuje; Yio fun o l’ayo oun ‘tunu Gbee wo lo s’ibi gbogbo Ooko ‘re… ti dun to! ‘Ret’ aiye, ayo orun Ook
Read hymn : F’ORUKO Jesu s’ okan reGBA aiye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O; Gba gbogbo akoko mi, Ki nwon kun fun iyin Re. Gba owo mi, k’ O si je Kin ma lo fun ife Re; Gba ese
Read hymn : GBA aiye mi, OluwaGBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re; Gb’eni damu w’alafia Nke p’oruko Re; Gba t’elese nwa iye, Kun
Read hymn : GBA alare nwa sinmiGBA Jesu ba de lati pin ere, B’ o j’ osan tabi l’ oru, Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona, Pel’ atupa wa tin tan? A le wip a mura tan ara, L
Read hymn : GBA Jesu ba de lati pin ereGBA mo le ka oye mi re, Ni ibugbe l’oke; Mo dagbere f’eru gbogbo, Mo n’omije mi nu. B’aiye kojuja s’okan mi, T’a nso oko si I, ‘Gbana mo le
Read hymn : GBA mo le ka oye mi reGBA t’ Olugbala w’ aiye, Anu j’ oba l’ okan Re, O nfi ibakedun han K’ O si gan enikeni. Afoju Aro y’ Ika, Aditi at’ abirun, Ko seni ti ko s
Read hymn : GBA t’ Olugbala w’ aiye