EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de
EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole, Eyini yio j’ ogo fun mi, Eyini yio j’ og
Read hymn : EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de643 hymns
EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole, Eyini yio j’ ogo fun mi, Eyini yio j’ og
Read hymn : EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio deEMI Mimo, ‘Dada orun, Wa li agbara Re; K’ o da ina ife mimo, Si okan tutu wa. Wo, b’ a ti nrapala nihin, T’ a fe ohun asan; Okan wa ko le f
Read hymn : EMI Mimo, ‘Dada orunEMI orun, gb’ adura wa, Wa gbe ‘nu ile yi, Sokale pel’ agbara Re, Wa, Emi Mimo wa. Wa b’ imole, si fihan wa B’ aini wa ti po to: Wa, to wa
Read hymn : EMI orun, gb’ adura waEMI wa ba w ape, L’ ojo isimi yi; Laisi Re awa ko le sin, A ko le gb’ adura. Asan li orin wa, Iwasu wa asan, Ipejopo wa ko l’ ere Afi b’ O
Read hymn : EMI wa ba w apeEMI ‘bukun, bi afefe, Ni nfe sibit’ o wu; Awon, t’ iji re lu, bawo L’ okan won ti yo to! O ntun okan ‘fe ara mo, O nte pa ese ba, O ns’ oka
Read hymn : EMI ‘bukun, bi afefeEMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi. Je kin mo ‘dariji Re; D’elese t’ eru npa ‘le; To mi si
Read hymn : EMI, Olore ofeENDE, korin Mose Ati t’ Odagutan; Ji, gbogbo okan at’ ahon , K’ e yin Olugbala. Korin ife ‘ku Re; At’ ipa ‘dide Re: Korin b’ O ti mbebe lok
Read hymn : ENDE, korin MoseENI ba gbekel’ Olorun, L’ abo l’ orun at’ aiye: Eni ba f’ ife wo Jesu, Ko s’ eru ti damu re. Lara Re nikan, Oluwa, Ni mo r’ adun itunu; Asa
Read hymn : ENI ba gbekel’ OlorunENI ‘subu se le Mo loju Olorun, Bi O ba tele pipe wa Ao subu lab’ egbe. Bi O ba fi oju Mimo be ‘wa wa wo,, A ha le ri awawi fun Eyo ese kan
Read hymn : ENI ‘subu se leENIKAN mbe t’ O feran wa, A! O fe wa! Ife Re ju t’ iyekan lo, A! O fe wa! Ore aiye nko wa sile, B’ oni dun, ola le koro, Sugbon Ore yi ko nt
Read hymn : ENIKAN mbe t’ O feran waENIKAN se ise wura; On wa b’ ore nigba aini; Enikan ko orin ayo, Nmu sanma dan ni gbogb’ ojo. Eni na ni o bi? Eni na ni o bi? Enikan ns’ o
Read hymn : ENIKAN se ise wuraENIT’ o ba gbo, kigbe iro na, Ran ihinrere na si gbogbo aiye Tan ihin na ka ‘bi gbogbo t’ enia wa, “Enit’ o ba fe le wa? “Enit’ o ba fe, Eni
Read hymn : ENIT’ o ba gbo, kigbe iro naENYIN Angel’ l’ orun ogo To yi gbogbo aiye ka, E ti ko ‘rin dida aiye, E so t’ ibi Messia, E wa josin Fun Kristi Oba titun. Enyin Oluso-agu
Read hymn : ENYIN Angel’ l’ orun ogoENYIN enia Olorun, Mo ti kiri aiye ka, To ‘pa ese on ‘kanu, Nko r’ itunu n’ ibikan. Okan mi pada sin yin, – Emi isansa, mo de; Nibi pepe ny
Read hymn : ENYIN enia OlorunENYIN ero, nibo l’e nlo T’ enyin t’ opa lowo nyin?” A nrin ajo mimo kan lo, Nipa ase Oba wa, Lori oke on petele, A nlo s’ afin Oba rere, A n
Read hymn : ENYIN ero, nibo l’e nloENYIN iran Adam, Da ohun orin po, Mo t’ orun at’ aiye, Lati yin Eleda; Enyin ogun angel’ didan E le ‘rin n’ile imole. Iwo orun didan, At’ o
Read hymn : ENYIN iran AdamENYIN omo oku, T’ o wa ninu ese, Gb’ ohun ihinrere, Jesu ranse si iyin. Enyin ent-egbe, e wa; Ni apa Jesu, aye mbe. E ma pe titi mo, Ma wa
Read hymn : ENYIN omo okuENYIN ti nkoja Ya sodo Jesu: O s’ asan fun nyin bi, bi Jesu ba ku? Alafia wa Onigbowo wa: Wa, wo b’ ibanuje kan ri bayi ri. Oluwa n’jo na,
Read hymn : ENYIN ti nkojaENYIN t’ e fe Oluwa, E fi ayo nyin han, E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun, K’ e si y’ ite na ka, K’ e si y’ ite na ka. A nyan lo si
Read hymn : ENYIN t’ e fe OluwaENYIN t’e f’oluwa, T’o mo ‘pa Re, e wa, E dapo n.isokan, Lati yin ore Re; F’orun at’aiye, e kede Oruko oludande yin. O f’ite Re loke, At’og
Read hymn : ENYIN t’e f’oluwaEREDI irokeke yi Ti enia ti now koja? ‘Jojumo n’ iwojopo na, Eredi re tin won nse be? Nwon dahun l’ ohun jeje pe, “Jesu ti Nasaret’ l’ O nko
Read hymn : EREDI irokeke yiEREDI iwa s’ aiye mi? ‘Tori kil’ a bi mi? Gbogb’ ohun l’ aiye l’ o n’ idi, Kil’ a ha da mi fun? Ninu gbogbo ohun t’ a da, Enia l’ o ga ju;
Read hymn : EREDI iwa s’ aiye miERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri. Mo sunmo, ‘te nla ni Mo sunmo’ okun kristali, Mo sunmo
Read hymn : ERO didun kan nsoESE mi po bi irawo, B’ iyanrin let’ okun; Sugbon iyonu Olorun, O papoju be lo. Manase, Paul on Magdalen, Iwo dariji won; Mo ti ka, mo si gb
Read hymn : ESE mi po bi irawo