BABA, je nya odun yi
BABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa: Bi ‘banuje on ‘rora Nko gbodo komnu; Eyi sa l’ adura mi. “Ogo f’ oko R
Read hymn : BABA, je nya odun yi643 hymns
BABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa: Bi ‘banuje on ‘rora Nko gbodo komnu; Eyi sa l’ adura mi. “Ogo f’ oko R
Read hymn : BABA, je nya odun yiBABA, mo n’ owo mi si O; Nko mo ‘ranwo miran: Bi O ba kuro lodo mi, A! nibo ni ngo lo? Ohun t’ OmoRe f’ ara da Ki nto la ‘ju s’ aiye! Ise t
Read hymn : BABA, mo n’ owo mi si OBABA, Omo, on Emi, Eni Metalokan lai, Jo, masai dabobo wa, K’ a le ri ‘mole ola.
Read hymn : BABA, Omo, on EmiBAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,” ‘Gba oro na wo ‘nu okan; A tan imole ka; Oro na ko ope l’ o
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBELESE s’owo po, Ti nwon nde s’Oluwa, Dimo si Kristi Re, Lati gan Oba na, B’aiye nsata, Pelu Esu, Eke ni nwon, Nwon nse lasan. Olugbala job
Read hymn : BELESE s’owo poBENI, O bikita fun mi, Pelu ike bi t’ egbon ; Beni, eru at’ ifoiya, Gbogbo re l’ O mba mi pin. Beni, fun mi li O mbebe, Ni ite-anu loke; Ni
Read hymn : BENI, O bikita fun miBI a ti f’ okan wa fun O Nip’ ase mimo Re, Ran s’ or’ omi, ‘Daba orun, F’ edidi t’ eje na. Ogo fun-Eniti a pa Nitor’ igbala wa, T’ O ran wa
Read hymn : BI a ti f’ okan wa fun OBI agbonrin ti nmi hele, S’ ipa odo omi; Beni okan mi nmi si O, Iwo Olorun mi. Orungbe Re ngbe okan mi, Olorun Alaye; Nigbawo ni ngo r’ oju
Read hymn : BI agbonrin ti nmi heleBI Jesu ba fe mi, Bi mo ba je Tire, Nko ko ohun t’ ota le ro, Bi nwon tile n’ ipa. Mo simi le ori Jesu, on eje Re; ‘Tori ninu Re nikan ni M
Read hymn : BI Jesu ba fe mi.BI mo egbarun ebun, Ngo di mo Jesu ti a pa, Y’o je ipile mi; ‘Tori ko s’ ipile miran, Ti mo le gbe ‘reti mi ka, Lehin Jesu nikan, Mo ni Kri
Read hymn : BI mo egbarun ebunBI mo ti ri – laisawawi, Sugbon nitori eje Re, B’O si ti pe mi pe ki nwa – Olugbala, mo de. Bi mo ti ri – laiduro pe, Mo fe k’okan mi mo to
Read hymn : BI mo ti ri – laisawawiBI o ti ri laisi ami Ife, ayo, tab’ ore kan, T’ o ye fun ibugbe orun, Elebi, ma bow a. Mo ru ese re lor’ igi; Mo gba ore t’ o to si o, K’ i
Read hymn : BI o ti ri laisi amiBI osun gbege eti ‘do, Tutu minimini; B’ igbo dudu eti omi, B’ itanna ipa ‘do. Be l’ omo na yio dagba, Ti nrin l’ ona rere T’ okan re nfa s
Read hymn : BI osun gbege eti ‘doBIBELI mimo t’ orun Owon isura t’ emi! ‘Wo ti nwi bi mo ti ri, ‘Wo ti nso bi mo ti wa. ‘Wo nko mi, bi mo sina, ‘Wo nf’ ife Oluwa han; ‘Wo l
Read hymn : BIBELI mimo t’ orunBIBEL’ iwe aiyeraiye Tani le ridi re? Tani le so idide re? Tani le m’ opin re? Asiri olodumare; Iko Oba orun Ida t’o pa oro iku; Aworan Olo
Read hymn : BIBEL’ iwe aiyeraiyeBO ti dun to l’ oj’ owo yi, Ojo t’ o dara ju, Ki a pa ‘ronu aiye Ki a pa ‘ronu nkan t’ orun! B’ o ti dun to lati l’ aye Bebe fun ‘dariji! K
Read hymn : BO ti dun to l’ oj’ owo yiBUKUN ni fun ohun, T’ o de wa po n’nu ‘fe; Idapo awon olufe, Dabi ijo t’ orun. Niwaju ‘te Baba, Li awa ngbadura; Okan n’ ireti at’ eru, Ati
Read hymn : BUKUN ni fun ohunB’ AWON ara igbani Ti f’ ayo ri ‘rawo na; Bi nwon ti f’ inu didun Tele ‘mole didan re; Be, Oluwa Olore Ni k’ a mu wa d’ odo Re. Bi nwon ti
Read hymn : B’ AWON ara igbaniB’ AYO aiye ti j’ asan to! Didara won ko pe! Ko s’ ayo ti ko l’ ororo, Adun re je ‘dekun. Gbogb’ ohun t’ o dara l’ aiye, Li o nfi etan dan,
Read hymn : B’ AYO aiye ti j’ asan toB’ ODO ti nyara san lo, Li ona gboro re, Ti omi re nja titi, T’ o nsare lo s’ okun, Beni aiye wan san lo, Ati ojo anu, Enia si nsare lo si ‘
Read hymn : B’ ODO ti nyara san loB’ ORUN l’ aiduro ti rin, La odun ti o lo ja Be l’ opo ti d’ opin won A ki o si ri won mo. A so won l’ ojo laiali, Tiwon pari li aiye; Awa
Read hymn : B’ ORUN l’ aiduro ti rinB’AIYE mi kun fun ‘banuje, O dara, o te mi l’orun; Laikun mo nreti ipe Re, Gbogbo nkan ni emi ntoro. Emi kio wa ayokayo, Lehin ki nle se if
Read hymn : B’AIYE mi kun fun ‘banujeB’ENU mi dun bi t’ awon ju, T’ ede mi ta t’ angeli yo; Laisi ife mo dab’ ide, Ti ohun re nhan ni l’ eti. Bi mo le f’ ogbon mi wasu Gbogbo n
Read hymn : B’ENU mi dun bi t’ awon juB’O ti dun lati gba Jesu Gbo gege bi oro Re; K’ a simi lor’ ileri Re, Sa gbogbo l’ Olyuwa wi. Jesu, Jesu emi gbagbo, Mo gbekele ngbagbogbo;
Read hymn : B’O ti dun lati gba Jesu