AGOGO ihinrere
AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi, Olorun f’ araiye T’ O fi Omo Re fun wa; P’ enikeni ti o gb’
Read hymn : AGOGO ihinrere643 hymns
AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi, Olorun f’ araiye T’ O fi Omo Re fun wa; P’ enikeni ti o gb’
Read hymn : AGOGO ihinrereAJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re? Ao ha gbe mi g’ oke orun Lori ‘busun ‘rorun, Gbati opo ja f’
Read hymn : AJAGUN Jesu l’ emi biAJIGBESE anu ni mi, Mo ti ba majemu mi je; Laifoya ninu pipe Re, Mo gb’ ara at ore mi wa. Eru ofin at’ Olorun Ko ri ipa sa lodo mi; Igboran
Read hymn : AJIGBESE anu ni miAKO ha gb’ oro wuwo ni, P’ a sin wa pelu Oluwa? P’ a te wa ri sinu ‘ku Re, A sib o ara osi ‘le. Okan wa gba emi t’ orun, A gbe kuro ninu ik
Read hymn : AKO ha gb’ oro wuwo niAKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun. A ko n’ ibugbe kan nihin, O buru b’ i
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinAKOKO ati lo mi ya, Mo gb’ ohun to npe mi lo ‘le, Olorun jek’ iyonu pin, Jek’ iranse Re ku l’ ayo. Mo ti sare ije mi tan, Ija pari, mo ti g
Read hymn : AKOKO ati lo mi yaAKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo. Gbat’ aniyan aiye jowo Ijoba aiya re lo
Read hymn : AKOKO ‘re gbat’ eda teALABUKUN n’ isun eje, T’ a fi han elese aiye; Olubukun n’ om Olorun, Nipa ‘na Re la wow a san, Bi mo ti nu lo l’ agbo Re Ti mo m’ egbe ba ok
Read hymn : ALABUKUN n’ isun ejeALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye; A ba je ka wa mo won, Laiye yi, ati l’ orun. Awon ti a da lare
Read hymn : ALABUKUN n’nu JesuALAFIA pel’ Oluwa, A, ede wo l’ eyi! A f’ eje b’ elese la ‘ja, Oto ‘simi l’ eyi. Ni iwa ati ni ise, Mo jina s’ Olorun; Sugbon ore-ofe fa mi
Read hymn : ALAFIA pel’ OluwaALAFIA w’ okan, t’ ohun re Ko apata l’ ohun aro: Dekun ejo wi, pa ‘nu mo, Ki ekun ye san l’ oju re; Wo, a ri ogun t’ o dara Lati tu o, ko ta
Read hymn : ALAFIA w’ okan, t’ ohun reALAFIA, li aiye ese yi, Eje Jesu nwipe, “Alafia!” Alafia, ninu opo lala? Lati se ife Jesu ni ‘simi. Alafia, n’nu igbi ‘banuje? L’ aiya Jes
Read hymn : ALAFIA, li aiye ese yiALAIMO lie mi, Olorun Oluwa! Emi ha gbodo sunmo O T’ emi t’ eru ese? Eru ese yii npa Okan buburu mi; Yio ha si ti buru to, L’ oju Re mimo n
Read hymn : ALAIMO lie miALAKOSO ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe l’ owo Re, Opin gbogbo l’ ase Re. Ase Re l’ o da aiye Ati ibi mi pelu, Obi, ile, on igba Ni
Read hymn : ALAKOSO ti orunALEJO kan ma nkankun, Pe E wole O ti npara ‘be tip e Pe E wole. Pe wole ki o to lo, Pe wole, Eni Mimo, Jesu Krist’ Omo Baba, Pe E wole! Sil
Read hymn : ALEJO kan ma nkankunALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d’ opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l’ a o ma ko. Alleluya! Gbogbo ipa n’ iku si lo: S
Read hymn : ALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!!AM’Oluwa iye Lo sinu ‘gbi mimo; Enit’ O wa gb’ okan wa la Ri l’ odo Jordani. O f’ ona jeje han, Ati ase mimo, O ni k’ awon t’ a ra gboran,
Read hymn : AM’Oluwa iyeAO ha pade l’ eti odo, T’ ese angeli ti te, ‘T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun? Ao ha pade l’ eti odo, Odo didan, odo didan na, Pel’
Read hymn : AO ha pade l’ eti odoAO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni wa, Jek’ a tele ona ti Oluwa wa to; K’ a f’ imoran Re so agbara wa d’ otun, K’ a fi gbogbo okun wa sise t’
Read hymn : AO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni waAPATA aiyeraiye, Se ibi isadi mi! Je ki omi on eje T’ o san lati iha Re Se iwosan f’ ese mi, K’ o si so mi di mimo. K’ ise ise owo mi, L’ o
Read hymn : APATA aiyeraiyeAPATA aiyeraiye, Enit’ o mbe lailai, Nigbakugba t’ iji nja, ‘Bugbe wa y’o gbe je: Saju dida aiye yi, Iwo mbe; bakanna Tit’ aiye ainipekun, A
Read hymn : APATA aiyeraiyeAPATA wa n’ ile are, Ojiji Re bo si iyanrin, O npe awon ero ti nkoja, Lati wa si boji l’ aginju. Etise t’ e o ku? Etise t’ e o ku? Nigbati
Read hymn : APATA wa n’ ile areARA e jek’ a jumo rin N’ ife on alafia; A ha le ma tun bere pe, O to k’ a ba f’ ija mo? Ni irepo L’ ayo, ife y’o fi po. B’ a ti nrin lo s’
Read hymn : ARA e jek’ a jumo rinARA mi fun ‘rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sise l’ oruko Jesu, Tit’ On o tun pada, wa, Nigbana ni a o f’ayo ka a, Olukore a ko won si
Read hymn : ARA mi fun ‘rugbin rere