EMI, Olore ofe
EMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi.
Read hymn : EMI, Olore ofeEMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi.
Read hymn : EMI, Olore ofeEMI anu, oto, ife, Ran agbara Re t’ oke wa; Mu iyanu ojo oni, De opin akoko gbogbo.
Read hymn : EMI anu, oto, ifeEMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole, Eyini yio j’ ogo fun mi,
Read hymn : EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio deEMI Mimo, ‘Dada orun, Wa li agbara Re; K’ o da ina ife mimo, Si okan tutu wa.
Read hymn : EMI Mimo, ‘Dada orunEMI orun, gb’ adura wa, Wa gbe ‘nu ile yi, Sokale pel’ agbara Re, Wa, Emi Mimo wa.
Read hymn : EMI orun, gb’ adura waEMI wa ba w ape, L’ ojo isimi yi; Laisi Re awa ko le sin, A ko le gb’ adura.
Read hymn : EMI wa ba w apeEMI ‘bukun, bi afefe, Ni nfe sibit’ o wu; Awon, t’ iji re lu, bawo L’ okan won ti yo to!
Read hymn : EMI ‘bukun, bi afefeENDE, korin Mose Ati t’ Odagutan; Ji, gbogbo okan at’ ahon , K’ e yin Olugbala.
Read hymn : ENDE, korin MoseENI ba gbekel’ Olorun, L’ abo l’ orun at’ aiye: Eni ba f’ ife wo Jesu, Ko s’ eru ti damu re.
Read hymn : ENI ba gbekel’ OlorunENIKAN mbe t’ O feran wa, A! O fe wa! Ife Re ju t’ iyekan lo, A! O fe wa!
Read hymn : ENIKAN mbe t’ O feran waENIKAN se ise wura; On wa b’ ore nigba aini; Enikan ko orin ayo, Nmu sanma dan ni gbogb’ ojo.
Read hymn : ENIKAN se ise wuraENIT’ o ba gbo, kigbe iro na, Ran ihinrere na si gbogbo aiye Tan ihin na ka ‘bi gbogbo t’ enia wa, “Enit’ o ba fe le wa?
Read hymn : ENIT’ o ba gbo, kigbe iro na