AFUN iho ayo mimu
AFUN iho ayo mimu S’ Olorun Oba nla! K’ile gbogbo lo ahon won K’o si korin ‘segun.
Read hymn : AFUN iho ayo mimuAFUN iho ayo mimu S’ Olorun Oba nla! K’ile gbogbo lo ahon won K’o si korin ‘segun.
Read hymn : AFUN iho ayo mimuISE ‘gbala pari, Jesu ti ba ‘ku ja, O se agbara iboji, O ti di asegun.
Read hymn : ISE ‘gbala pariIFE orun alailegbe, Ayo orun sokale: Fi okan wa se ‘bugbe Re, Se asetan anu Re;
Read hymn : IFE orun alailegbeGBOGBO aiye, gbe jesu ga, Angeli’, e wole fun: E mu ade Oba Re wa, Se l’Oba awon oba.
Read hymn : GBOGBO aiye, gbe jesu gaENDE, korin Mose Ati t’ Odagutan; Ji, gbogbo okan at’ ahon , K’ e yin Olugbala.
Read hymn : ENDE, korin MoseGB’ opo duru pelu ohun Nwon nkorin iyin loke; Jesu joba, orun si yo; Olorun ife joba;
Read hymn : GB’ opo duru pelu ohunEYO Jesu joba N’nu omo enia, O da ara tubu, O so won d’omnira:
Read hymn : EYO Jesu joba“MO mo p’Oludande mi mbe;” Itunu nla l’eyi fun mi! O mbe, Enit’ o ku lekan; O mbe, Ori iye mi lai.
Read hymn : MO mo p’Oludande mi mbeEMI ‘bukun, bi afefe, Ni nfe sibit’ o wu; Awon, t’ iji re lu, bawo L’ okan won ti yo to!
Read hymn : EMI ‘bukun, bi afefeSO itan kanna fun mi, T’ ohun ni t’ a ko ri; Ti Jesu on ogo Re, Ti Jesu En ‘ ife,
Read hymn : SO itan kanna fun miOLUWA, y’o ti pe to T’ Iwo o tun pada; Are fere mu wa tan, Bi a ti nw’ ona Re;
Read hymn : OLUWA, y’o ti pe toJI, apa Olorun, k’ o ji, Gbe ‘pa Re wo, mi or’ ile; Ni sisin Re, je k’ aiye ri Isegun ise anu Re.
Read hymn : JI, apa Olorun, k’ o ji