JEJE, lai si ariwo
JEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re;
Read hymn : JEJE, lai si ariwoJEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re;
Read hymn : JEJE, lai si ariwoEnyin okan tie bi npa, T’o nf’ategun s’onje, T’o nja lasan, lati nkan Aiye b’okan ebi.
Read hymn : JE ki gbogbo eti ko gboJEKI m’ n’ ipo mi lodo Re, Jesu, Iwo isimi mi; ‘Gbana l’ okan mi y’o simi Y’o si ri ekun ‘bukun gba.
Read hymn : JEKI m’ n’ ipo mi lodo ReJEK’ alore Sion dide Gba ipe fun ‘ra won; Jeki nwon gba ase wuwo Lat’ enu Oluwa.
Read hymn : JEK’ alore Sion dideJE ni imole ojo Para kuro loju mi, Lala mi rekoja lo, Ngo ba Oluwa soro.
Read hymn : JE ni imole ojoJE ran orun kekere nibiti o nlo, Se ranlowo lati le okunkun l’ aiye, ‘Wo o ri b’ okunkun yio ti lo kuro, B’ iwo ba je ‘mole njojumo.
Read hymn : JE ran orun kekere nibiti o nloJERUSALEM ibi ayo, T’ o se owon fun mi; ‘Gbawo n’ ise mi yio pari, L’ ayo, l’ alafia?
Read hymn : JERUSALEM ibi ayoJERUSALEM t’ orun, Orin mi, ilu mi! Ile mi bi mba ku, Ekun ibukun mi;
Read hymn : JERUSALEM t’ orunJESU, a fe pade, L’ ojo Re mimo yi; A si y’ ite Re ka, L’ ojo Re mimo yi;
Read hymn : JESU, a fe padeJESU, agbara mi, Iwo l’ aniyan mi, Emi fi igbagbo w’ oke, Iwo l’ O ngb’adua.
Read hymn : JESU, agbara miJESU, aso ododo Re L’ ewa at’ ewu ogo mi, L’ aiye etan bi mba gbe wo, L’ ayo ni ngo gb’ ori s’ oke.
Read hymn : JESU, aso ododo ReJESU, bukun wa k’ a to lo: Gbin oro Re si aiya wa: K’ o si mu k’ ife gbigbona Kun okan ilowo wa:
Read hymn : JESU, bukun wa k’ a to loJESU, ise Re l’o Fi ayo s’okan mi, Nwon ni, o ti pari, Ki eru mi ko tan:
Read hymn : JESU, ise Re l’oJESU, Iwo li a nwo, K’ a repo l’ oruko Re; Alade alafia, Mu k’ ija tan larin wa.
Read hymn : JESU, Iwo li a nwoJESU, kiki ironu Re, Fi ayo kun okan; Sugbon k’ a ri O l’ o dun ju, K’ a simi lodo Re.
Read hymn : JESU, kiki ironu ReJESU, nib’ eni Re pade, Nibe nwon r’ ite anu Re; Nibe nwon wa O, nwon ri O, Ibikibi n’ ile owo.
Read hymn : JESU, nib’ eni Re padeJESU, nigba aiye Re, O ko dekun wo arun; Igbe irora aisan Ko kan O k’ o bo ‘le ri.
Read hymn : JESU, nigba aiye ReJESU, Oba nla ni Sion, ‘Wo ni yio j’ amona wa; Ase Re li a gbekele, Iwo nikan l’ ao tele.
Read hymn : JESU, Oba nla ni SionJESU, O ha re ‘ra Re le Gbat’ O gb’ ara wa wo? Lati se awotan aisan, Lati l’ arun jade?
Read hymn : JESU, O ha re ‘ra Re leJESU, Oluwa or’-ofe, ‘Wo imole oju Baba, Kanga ‘mole aiyeraiye, T’ ase Re l’ okun ale lo.
Read hymn : JESU, Oluwa or’-ofeJESU, Ore ‘lese ni O; B’ elese, mo now O; Lat’ inu ekun ife Re, Oluwa, ranti mi.
Read hymn : JESU, Ore ‘lese ni OJESU, ‘ Wo Olus’-agutan, Pa agbo Re kekere mo; Gb’ awon agutan Re wonyi, Ma jekii nwon ko gbo lai.
Read hymn : JESU, ‘ Wo Olus’-agutanJESU a de l’ ojo oni Lati se ase Re, Jo masai wa si arin wa, K’ O f’ ola Re ran wa.
Read hymn : JESU a de l’ ojo oniJESU alail’ abawon, O ti f’ eje Re ra mi, Nko nani ohunkohun, Lehin agbelebu Re.
Read hymn : JESU alail’ abawon