ENYIN Angel’ l’ orun ogo
ENYIN Angel’ l’ orun ogo To yi gbogbo aiye ka, E ti ko ‘rin dida aiye, E so t’ ibi Messia,
Read hymn : ENYIN Angel’ l’ orun ogo643 hymns
ENYIN Angel’ l’ orun ogo To yi gbogbo aiye ka, E ti ko ‘rin dida aiye, E so t’ ibi Messia,
Read hymn : ENYIN Angel’ l’ orun ogoENYIN enia Olorun, Mo ti kiri aiye ka, To ‘pa ese on ‘kanu, Nko r’ itunu n’ ibikan.
Read hymn : ENYIN enia OlorunENYIN ero, nibo l’e nlo T’ enyin t’ opa lowo nyin?” A nrin ajo mimo kan lo, Nipa ase Oba wa,
Read hymn : ENYIN ero, nibo l’e nloENYIN iran Adam, Da ohun orin po, Mo t’ orun at’ aiye, Lati yin Eleda;
Read hymn : ENYIN iran AdamENYIN omo oku, T’ o wa ninu ese, Gb’ ohun ihinrere, Jesu ranse si iyin.
Read hymn : ENYIN omo okuENYIN ti nkoja Ya sodo Jesu: O s’ asan fun nyin bi, bi Jesu ba ku?
Read hymn : ENYIN ti nkojaENYIN t’ e fe Oluwa, E fi ayo nyin han, E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun,
Read hymn : ENYIN t’ e fe OluwaENYIN t’e f’oluwa, T’o mo ‘pa Re, e wa, E dapo n.isokan, Lati yin ore Re;
Read hymn : ENYIN t’e f’oluwaEREDI irokeke yi Ti enia ti now koja? ‘Jojumo n’ iwojopo na, Eredi re tin won nse be?
Read hymn : EREDI irokeke yiEREDI iwa s’ aiye mi? ‘Tori kil’ a bi mi? Gbogb’ ohun l’ aiye l’ o n’ idi, Kil’ a ha da mi fun?
Read hymn : EREDI iwa s’ aiye miERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri.
Read hymn : ERO didun kan nsoESE mi po bi irawo, B’ iyanrin let’ okun; Sugbon iyonu Olorun, O papoju be lo.
Read hymn : ESE mi po bi irawo