ERO didun kan nso
ERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri.
Read hymn : ERO didun kan nsoERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri.
Read hymn : ERO didun kan nsoESE mi po bi irawo, B’ iyanrin let’ okun; Sugbon iyonu Olorun, O papoju be lo.
Read hymn : ESE mi po bi irawoESE ti e ko le sailo Emi nyin danu lor’ asan, Ti ohun kanso, na t’ o ye, Ko si n’nu gbogbo ero nyin?
Read hymn : ESE ti e ko le sailoESE t’ onigbagbo mberu? Kini ‘ba ma da won l’ amu? Iku Jesu le ‘foya lo, O mu isimi sokale.
Read hymn : ESE t’ onigbagbo mberuETUN won ko fun mi ki ngbo Oro ‘yanu t’ Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro ‘yanu t’ Iye,
Read hymn : ETUN won ko fun mi ki ngboEWA otosi elese, Wa li akoko anu; Jesu nduro lati gba nyin, O kun fun ‘fe at’ ipa;
Read hymn : EWA otosi eleseEWE ti Oba orun, Korin didun b’ e ti nlo; Korin ‘yin t’ Olugbala, Ise Enit’ o l’ ogo.
Read hymn : EWE ti Oba orunEWOLE f’ Oba, ologo julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni, at’ Eni Igbani, O ngbe ‘nu ogo, eleru ni iyin.
Read hymn : EWOLE f’ Oba, ologo juloEYI, e yipada, ese t’ e o ku, Nigbat’ Olorun sunmo wa li anu? Jesu npe nyin, Emi sin wipe k’ e wa, Angeli si nduro lati mu nyin lo.
Read hymn : EYI, e yipada, ese t’ e o kuEYI l’ ojo Oluwa da, O pe ‘gba na n Tire; K’ orun ko yo, k’ aiye k’ o yo, K’ iyin y’ ite na ka.
Read hymn : EYI l’ ojo Oluwa daE Yin Oluwa, e tun ohun se, Lati korin Re ninu ajo nla; E je k’ aiye yo ninu Eleda won, K’ akobi igbala yo n nu Oba won.
Read hymn : E Yin Oluwa, e tun ohun seEYO, eyin mimo, e yin Ibukun; anu, igbala, Jesu oke nyin titi lai, D’ oju ko agbara iji.
Read hymn : EYO, eyin mimo, e yin