OGO fun Olorun Baba
OGO fun Olorun Baba, Ogo f’ Olorun Omo, Ogo fun Olorun Emi, Jehofa, Metalokan;
Read hymn : OGO fun Olorun BabaOGO fun Olorun Baba, Ogo f’ Olorun Omo, Ogo fun Olorun Emi, Jehofa, Metalokan;
Read hymn : OGO fun Olorun BabaA F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun:
Read hymn : A F’ iyin aiku funF’ ORUK’ Olorun loke, T’ O l’ agbara at’ ola, Olorun ibi gbogbo, N’ iyin ati ogo wa.
Read hymn : F’ ORUK’ Olorun lokeOLORUN ti fi Jesu se Etutu fun ese; On na l’ okan mi duro ti, Ninu igbagbo mi,
Read hymn : OLORUN ti fi Jesu seOLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je.
Read hymn : OLUWA, alaimo l’ emiENI ‘subu se le Mo loju Olorun, Bi O ba tele pipe wa Ao subu lab’ egbe.
Read hymn : ENI ‘subu se leOLUWA, bawo l’ okan mi Ti bale lekan ri; Mo wa laye laisi ofin, Mo seb’ ese mi ku.
Read hymn : OLUWA, bawo l’ okan miASAN n’ ireti t’ enia ko Le ori ise won: A bi won pel’ okan eri, Ebi si n’ iwa won.
Read hymn : ASAN n’ ireti t’ enia koGBAT’ emi re ba fo lo, T’ iku ba siji bo o; ‘Gbati sa re ba pari, Elese n’ bo l’ o yo si?
Read hymn : GBAT’ emi re ba fo loNIBO n’ isimi wa Fun okan alare? Asan ni lati w’ aiye ka, Lati wa ‘le okun.
Read hymn : NIBO n’ isimi waLONI ni Jesu pe! Asako wa; A! okan okunkun Ma kiri mo.
Read hymn : LONI ni Jesu peELESE kil’ o ni t’ o Jo ayo onigbagbo? Pelu ododo riro, Ona re dun to ti ‘wa
Read hymn : ELESE kil’ o ni t’ o