ADUA didun adua didun
ADUA didun adua didun, T’o gbe mi lo kuro l’aiye, Lo ‘waju ite Baba mi, Ki nso gbogbo edun mi fun;
Read hymn : ADUA didun adua didunADUA didun adua didun, T’o gbe mi lo kuro l’aiye, Lo ‘waju ite Baba mi, Ki nso gbogbo edun mi fun;
Read hymn : ADUA didun adua didunIGBAGBO mi nwo O, Iwo Od’-agutan, Olugbala Jo gbo adua mi,
Read hymn : IGBAGBO mi nwo OTIRE l’ awa Kristi, Titi aiyeraiye, A fe fi gbogbo okan wa Fun O patapata.
Read hymn : TIRE l’ awa KristiB’ AYO aiye ti j’ asan to! Didara won ko pe! Ko s’ ayo ti ko l’ ororo, Adun re je ‘dekun.
Read hymn : B’ AYO aiye ti j’ asan toJESU, agbara mi, Iwo l’ aniyan mi, Emi fi igbagbo w’ oke, Iwo l’ O ngb’adua.
Read hymn : JESU, agbara miBUKUN ni fun ohun, T’ o de wa po n’nu ‘fe; Idapo awon olufe, Dabi ijo t’ orun.
Read hymn : BUKUN ni fun ohunB’ENU mi dun bi t’ awon ju, T’ ede mi ta t’ angeli yo; Laisi ife mo dab’ ide, Ti ohun re nhan ni l’ eti.
Read hymn : B’ENU mi dun bi t’ awon juARA e jek’ a jumo rin N’ ife on alafia; A ha le ma tun bere pe, O to k’ a ba f’ ija mo?
Read hymn : ARA e jek’ a jumo rinJESU, Iwo li a nwo, K’ a repo l’ oruko Re; Alade alafia, Mu k’ ija tan larin wa.
Read hymn : JESU, Iwo li a nwoWO! b’ o ti dun to lati ri Awon ara t’ o re; Ara ti okan won s’ okan, L’ egbe ide mimo.
Read hymn : WO! b’ o ti dun to lati riGBEKE re le Oluwa, F’ oro Re s’ agbara re; Y’o duro ti o lailai, B’ orun tile koja lo.
Read hymn : GBEKE re le OluwaMO duro de Olorun mi, O si gbo igbe mi, O ri mo simi l’ oro Re, O si mu ‘gbala wa.
Read hymn : MO duro de Olorun miABA le n’ igbagbo aye, B’ o ti wu k’ ota po; Igbagbo ti ko je mira Fun aini at’ os
Read hymn : ABA le n’ igbagbo ayeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa.
Read hymn : IFE orun t’ o teribaISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi, Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de; Simi okan mi, eyikeyi t’ o de, O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya.
Read hymn : ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yiIGBA wa mbe li owo Re, A fe ko wa nibe; A fie mi at’ ara wa Si abe iso Re.
Read hymn : IGBA wa mbe li owo ReNIHIN l’ ayida wa, Ojo, erun nkoja; Ile ni nyan, ti o si nsa, ‘Tana dada si nku;
Read hymn : NIHIN l’ ayida waA IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si.
Read hymn : A IGBAGBO bila! T’ emi l’ OluwaOLORUN Olodumare, Alanu, Olore, Iwo l’ O da gbogbo aiye, Ati orun pelu.
Read hymn : OLORUN OlodumareOLUWA, ki s’agbara mi Bi mo ye, bi mo ku; Lati sin O ni ipin mi, Iwo ni si fun ni.
Read hymn : OLUWA, ki s’agbara miB’AIYE mi kun fun ‘banuje, O dara, o te mi l’orun; Laikun mo nreti ipe Re, Gbogbo nkan ni emi ntoro.
Read hymn : B’AIYE mi kun fun ‘banujeONA Re, Oluwa, B’ o ti wu k’ o su to, Masai f’ owo ‘tun Re to mi, Yan ipa mi fun mi.
Read hymn : ONA Re, OluwaMA toju, Jehofah nla, Ero l’ aiye osi yi, Emi ko l’ okun, iwo ni, F’ ow’ agbara di mi mu,
Read hymn : MA toju, Jehofah nlaBABA mi, ‘gba mo nsako lo, Kuro l’ ona Re l’ aiye yi; Ko mi kin le bayi pe, Se ‘fe Tire.
Read hymn : BABA mi, ‘gba mo nsako lo