BAWO ni awon ewe wa
BAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,”
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,”
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBIBEL’ iwe aiyeraiye Tani le ridi re? Tani le so idide re? Tani le m’ opin re?
Read hymn : BIBEL’ iwe aiyeraiyeIWO Oro Olorun, Ogbon at’ oke wa, Oto ti ki ‘yipada, Imole aiye wa;
Read hymn : IWO Oro OlorunIWE kan wa ti kika ra, Ko soro fun enia, Ogbon ti awon t’o ka nfe, Ni okan ti o mo.
Read hymn : IWE kan wa ti kika raTORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo;
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrereIWO oro t’o tobi, Ninu eyit ‘a ri, Ileri ati sise Awamaridi ni:
Read hymn : IWO oro t’o tobiJESU, Oba nla ni Sion, ‘Wo ni yio j’ amona wa; Ase Re li a gbekele, Iwo nikan l’ ao tele.
Read hymn : JESU, Oba nla ni SionJESU mo bg’ agbelebu mi, Ki nle ma to O lehin; Otosi at’ eni egan, ‘Wo l’ ohun gbogbo fun mi;
Read hymn : JESU mo bg’ agbelebu miENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbala Nip’ eje Od’-agutan, E gbo ohun isipaya, Erin ‘na ti Jesu rin.s
Read hymn : ENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbalaAM’Oluwa iye Lo sinu ‘gbi mimo; Enit’ O wa gb’ okan wa la Ri l’ odo Jordani.
Read hymn : AM’Oluwa iyeN’IFE l’ a te ona T’ Olugbala ti rin; A f’ apere Olori wa, Agutan Olorun.
Read hymn : N’IFE l’ a te onaL’ONA gbogbo t’ Oluwa yan, Ajo mi l’ emi o to; Ma da mi ro, eyin mimo, Emi o ban yin lo.
Read hymn : L’ONA gbogbo t’ Oluwa yanJESU t’ O wa gba mi la, Wo ‘nu odo Jordani, O jade kuro n’nu re, A si m’ O l’ Om’-Olorun,
Read hymn : JESU t’ O wa gba mi laEJERI, angel’ enia Niwaju Oluwa, On l’ awa mba da majemu, T’ a ko gbodo baje.
Read hymn : EJERI, angel’ eniaOLUWA, nje ‘dariji Re Yio gb’ eni bi emi? Nje, O gbe ese mi kuro O f’ erin bukun mi?
Read hymn : OLUWA, nje ‘dariji ReOJO ayo l’ ojo ti mo Yan O, ‘Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’ o si s’ ayo re kakiri
Read hymn : OJO ayo l’ ojo ti moA BAPTIS’ wa sinu iku, Nipa itebo ‘mi; A sin wa ‘nu ‘boji Jesu, A sin wa pelu Re.
Read hymn : A BAPTIS’ wa sinu ikuJESU ni, “Gb’ agbelebu re Ki o si ma tele Mi,” Oro yi ha le mu wag bon? A o ha sa fun eru na?
Read hymn : JESU ni, “Gb’ agbelebu reAKO ha gb’ oro wuwo ni, P’ a sin wa pelu Oluwa? P’ a te wa ri sinu ‘ku Re, A sib o ara osi ‘le.
Read hymn : AKO ha gb’ oro wuwo niONIGBAGBO, e wo Oluwa nyin n’nu ‘se, A ri s inu okun ‘rora, T’ o b’ okan Re mo ‘le.
Read hymn : ONIGBAGBO, e woBI a ti f’ okan wa fun O Nip’ ase mimo Re, Ran s’ or’ omi, ‘Daba orun, F’ edidi t’ eje na.
Read hymn : BI a ti f’ okan wa fun OOLUWA orun at’ aiye! Jesu, Omo ninu ara! Emi Mimo fun ‘toju wa! E gbo, ki E si gb’ eje wa.
Read hymn : OLUWA orun at’ aiyeWO t’ O teriba nin’ odo Jordani, T’ O mokun n’nu ‘banuje wa, t’ O si ku T’ O jinde ninu okunkun sin’ ogo, T’ O si gba ‘joba ife awon Tire.
Read hymn : WO t’ O teriba nin’ odo JordaniDAB’ orun sokale, Si fi ara Re han, F’ife Oluwa han F’ edidi Re di wa,
Read hymn : DAB’ orun sokale