GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de
GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe!
Read hymn : GBAT’ O ba de, gbat’ O ba deGBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe!
Read hymn : GBAT’ O ba de, gbat’ O ba deGBAT’ oju mi ba se peki ‘Mole to se n’ ila orun, Orun ododo masai ran Ase anu re s’ ori mi,
Read hymn : GBAT’ oju mi ba se pekiGBAT’ okan are fe ‘simi, T’ o nwa Olorun re, B’ o ti dun to lati r’ ale T’ o pin ose lala.
Read hymn : GBAT’ okan are fe ‘simiGBA t’ Olugbala w’ aiye, Anu j’ oba l’ okan Re, O nfi ibakedun han K’ O si gan enikeni.
Read hymn : GBA t’ Olugbala w’ aiyeGBA ‘Wo Onidajo ba de Lati m’ awon Tire lo ‘le, Ngo ha wa l’ arin won? Ao ha r’ ekolo lasan yi,
Read hymn : GBA ‘Wo Onidajo ba deGBEKELE ojojumo, ‘Gbekele ninu iji, B’ igbgbo tile kere, Ki nsa gbekele Jesu.
Read hymn : GBEKELE ojojumoGBEKELE onigbagbo, B’ ija na tile pe, Sibe iwo yio segun, Olorun ja fun o.
Read hymn : GBEKELE onigbagboGBEKE re le Oluwa, F’ oro Re s’ agbara re; Y’o duro ti o lailai, B’ orun tile koja lo.
Read hymn : GBEKE re le OluwaGBO! Orin ti Jubili, O dabi sisan ara; Tabi bi kikun okun, Gbat’ igbi re ba nlu ‘le
Read hymn : GBO! Orin ti JubiliGBO-GB’ ogo iyin ola, Fun O oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun!
Read hymn : GBO-GB’ ogo iyin olaGBO ase ti Jesu pa, “Lo wasu ‘hinrere Mi, Enikeni t’ o gbagbo, T’ a si tebomi, yio la.”
Read hymn : GBO ase ti Jesu paGBO eda orun nkorin, “Ogo fun Oba t’ a bi.” “Alafia l’ aiye yi,” Olorun ba wa laja,
Read hymn : GBO eda orun nkorin