MO gbeke mi le O
MO gbeke mi le O, Lori ibusun mi, Gba mi lowo irora mi, Ki O si wo mi san.
Read hymn : MO gbeke mi le OMO gbeke mi le O, Lori ibusun mi, Gba mi lowo irora mi, Ki O si wo mi san.
Read hymn : MO gbeke mi le OMO gbohun Jesu t’ o wipe, “Wa simi lodo Mi; Gbe ori re, ‘wo alare, Le okan aiya Mi.”
Read hymn : MO gbohun Jesu t’ o wipeMO ha le tun duro Laif’ ini mi toro? Ki nmu okan kuro l’ aiye, Ki ngba Olugbala?
Read hymn : MO ha le tun duroMO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajeji, Ile mi jin rere, l’or’ ebute wura; Lati je iranse n’koja okun l’ohun, Mo nsise nihin f’ oba mi
Read hymn : MO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajejiMOKANDILOGORUN dubule je, Labe oji nin’ agbo; Sugbon okan je lo s’ or’ oke, Jina s’ ilekun wura;
Read hymn : MOKANDILOGORUN dubule jeMO korin ipa Olorun, T’ O gbe oke dide, T’ O tan odo tin san kiri, T’ O si k’ orun giga.
Read hymn : MO korin ipa OlorunMO k’ ese mi le Jesu, Od’ agutan mimo; O ru gbogbo eru mi, O so mi d’ominira;
Read hymn : MO k’ ese mi le Jesu“MO mo p’Oludande mi mbe;” Itunu nla l’eyi fun mi! O mbe, Enit’ o ku lekan; O mbe, Ori iye mi lai.
Read hymn : MO mo p’Oludande mi mbeMO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo, On na ko ko ni bi ore aiye sa; Tifetife li on nse ajo lori mi, Mo fe k’ Olugbala mi si je tire.
Read hymn : MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogoMO n’ ‘ore, kan, A, Ore na! N’ ife mi k’ emi to mo, On f’ okun ife Re nla, Fa mi sunmo odo Re,
Read hymn : MO n’ ‘ore, kan, A, Ore naMO ti mb’ese rin ti pe, Pin wa n’iya, Oluwa, Ore’parun ni tire, Gba mi Jesu, mo segbe.
Read hymn : MO ti mb’ese rin ti peMO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado;
Read hymn : MO ti ni Jesu l’oreMO ti se ‘leri, Jesu, Lati sin O d’ opin; Ma wa lodo mi titi, Baba mi, Ore mi,
Read hymn : MO ti se ‘leri, JesuMO yo pipo pe Baba wa orun So t’ife Re ninu ‘we t’o fun mi, Mo r’ ohun ‘yanu ninu Bibeli, Eyi sowon ju pe Jesu fe mi,
Read hymn : MO yo pipo pe Baba wa orunMURA ebe, okan mi Jesu nfe gb’ adura re; O tip e k’ o gbadura, Nitorina yio gbo.
Read hymn : MURA ebe, okan miMURA elese lati gbon, Ma duro de ojo ola; Niwon b’ o ti kegan ogbon, Be l’ o si soro lati ri.
Read hymn : MURA elese lati gbonNAIJIRIA, a ki o, Orile wa owon Eya, ede le yato A duro ni ‘sokan,
Read hymn : NAIJIRIA, a ki oNGO fe O, Olorun Baba, Olugbala, Oba mi; Ngo fe O, ‘tori laisi Re Aiye j’ ohun kikoro.
Read hymn : NGO fe O, Olorun BabaNGO feran Re, Wo odi mi; Ngo feran Re, ‘Wo ayo mi; Ngo feran Re, patapata; Ngo feran Re, tor’ ise Re,
Read hymn : NGO feran Re, Wo odi miNGO ha ku ni owo ofo, Ki mba oluwa mi be Ko ti fun u n’ise ojo kan, Ikogun fun On ko si.
Read hymn : NGO ha ku ni owo ofoNGO je ‘mole fun Jesu, Ki ntan nigba gbogbo, Ki ntan s’ ibi to fe mi, Ki ntan l’ojojumo,
Read hymn : NGO je ‘mole fun JesuNGO korin itan ‘yanu na, Ti Jesu t’ o ku fun mi, B’ On ti fi ‘le ogo sile, F’agbelebu Kalfari.
Read hymn : NGO korin itan ‘yanu naNGO sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O; B’ o tile se ‘ponju, L’ o mu mi wa;
Read hymn : NGO sunm’ O, OlorunNI akoko ipinya, Jeki a fi ara wa, S’ abe oju at’ okan, Ore korikosun wa.
Read hymn : NI akoko ipinya