OJO mefa t’ ise koja
OJO mefa t’ ise koja, Okan t’ isimi si bere; Pada okan mi wa ‘simi, Yo s’ ojo t’ Oluwa busi.
Read hymn : OJO mefa t’ ise kojaOJO mefa t’ ise koja, Okan t’ isimi si bere; Pada okan mi wa ‘simi, Yo s’ ojo t’ Oluwa busi.
Read hymn : OJO mefa t’ ise kojaJI, enyin mimo ji, E k’ ojo owo yi, E fi orin iyin At’ ayo juba Re;
Read hymn : JI, enyin mimo jiKABO ojo ‘simi T’ o r’ ajinde Jesu; Ma bowa s’ okan ti nsoji, At’ oju ti nyo yi!
Read hymn : KABO ojo ‘simiOJO ‘simi at’ ayo Ojo inu didun, Etutu fun wahala, T’ o dara, t’ o si ndan!
Read hymn : OJO ‘simi at’ ayoBO ti dun to l’ oj’ owo yi, Ojo t’ o dara ju, Ki a pa ‘ronu aiye Ki a pa ‘ronu nkan t’ orun!
Read hymn : BO ti dun to l’ oj’ owo yiIMOLE ojo ‘simi Je l’ o ku mo wa l’ oju, B’ igbat’ orun iba wo, Fun ajo onigbagbo.
Read hymn : IMOLE ojo ‘simiBABA, aniyan at’ eru Le su l’ ojo ola, Sugbon ‘foya ko le wo ‘bi; Tire l’ ojo oni.
Read hymn : BABA, aniyan at’ eruOLUWA, isimi Re dun; Sugbon t’ oke ju ti aiye lo; Sibe pelu ‘reti ayo Li okan ongbe wa nsare.
Read hymn : OLUWA, isimi Re dunGBOGB’ ogun orun nro keke, Angeli mu harpu won, Awon mimo nt’ ohun won se Lati josin t’ o l’ ogo;
Read hymn : GBOGB’ ogun orun nro kekeEMI wa ba w ape, L’ ojo isimi yi; Laisi Re awa ko le sin, A ko le gb’ adura.
Read hymn : EMI wa ba w apeABE, a fe ri o, Ojo ‘simi rere, Gbogbo ose a ma wipe, Iwo o ti pe to?
Read hymn : ABE, a fe ri oJESU, a fe pade, L’ ojo Re mimo yi; A si y’ ite Re ka, L’ ojo Re mimo yi;
Read hymn : JESU, a fe padeOSE, ose rere, Iwo ojo ‘simi; O ye k’ a fi ojo kan, Fun Olorun rere;
Read hymn : OSE, ose rereOJO ‘mole l’ eyi, K’ imole wa l’oni; ‘Wo, Orun, ran s’ okunkun wa, K’o si le oru lo.
Read hymn : OJO ‘mole l’ eyiEYI l’ ojo Oluwa da, O pe ‘gba na n Tire; K’ orun ko yo, k’ aiye k’ o yo, K’ iyin y’ ite na ka.
Read hymn : EYI l’ ojo Oluwa daJESU a w’ odo Re L’ ojo Re mimo yi; To wa wa ba wa ti pejo, Si ko wa fun ‘ra Re.
Read hymn : JESU a w’ odo ReFI ibukun Re tu wa ka, Fi ayo kun okan wa; K’ olukuluku mo ‘fe Re, K’ a l’ ayo n’ nu ore Re,
Read hymn : FI ibukun Re tu wa kaOLORUN awa fe, Ile t’ ola Re wa; Ayo ibugbe Re Ju gbogbo ayo lo.
Read hymn : OLORUN awa feLI o wuro Iwo o gbo Ohun mi, Oluwa; S’ odo Re l’ emi o dari Oju adura mi.
Read hymn : LI o wuro Iwo o gboNI kutu, mo de Oluwa Lati wa oju Re, Okan ongbe mi da ‘ku lo, Lais’ ayo ore Re.
Read hymn : NI kutu, mo de OluwaJESU bukun oro Re, K’ o le tete f’ ipa han; Ki elese gbo ‘pe Re, K’ enia Re dagba n’nu ‘fe.
Read hymn : JESU bukun oro ReAKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo.
Read hymn : AKOKO ‘re gbat’ eda teJI okan mi, ba orun ji, Mura si ise ojo re; Ma se ilora, ji kutu, K’ o san ‘gbese ebo oro.
Read hymn : JI okan mi, ba orun jiOLORUN kutu ohun Re L’ o mu orun f’ ayo dide, Inu re dun bi omiran, Lati sare yi sanma ka.
Read hymn : OLORUN kutu ohun Re