AGOGO ihinrere
AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrere643 hymns
AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrereAJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re?
Read hymn : AJAGUN Jesu l’ emi biAJIGBESE anu ni mi, Mo ti ba majemu mi je; Laifoya ninu pipe Re, Mo gb’ ara at ore mi wa.
Read hymn : AJIGBESE anu ni miAKO ha gb’ oro wuwo ni, P’ a sin wa pelu Oluwa? P’ a te wa ri sinu ‘ku Re, A sib o ara osi ‘le.
Read hymn : AKO ha gb’ oro wuwo niAKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun.
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinAKOKO ati lo mi ya, Mo gb’ ohun to npe mi lo ‘le, Olorun jek’ iyonu pin, Jek’ iranse Re ku l’ ayo.
Read hymn : AKOKO ati lo mi yaAKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo.
Read hymn : AKOKO ‘re gbat’ eda teALABUKUN n’ isun eje, T’ a fi han elese aiye; Olubukun n’ om Olorun, Nipa ‘na Re la wow a san,
Read hymn : ALABUKUN n’ isun ejeALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye;
Read hymn : ALABUKUN n’nu JesuALAFIA pel’ Oluwa, A, ede wo l’ eyi! A f’ eje b’ elese la ‘ja, Oto ‘simi l’ eyi.
Read hymn : ALAFIA pel’ OluwaALAFIA w’ okan, t’ ohun re Ko apata l’ ohun aro: Dekun ejo wi, pa ‘nu mo, Ki ekun ye san l’ oju re;
Read hymn : ALAFIA w’ okan, t’ ohun reALAFIA, li aiye ese yi, Eje Jesu nwipe, “Alafia!”
Read hymn : ALAFIA, li aiye ese yiALAIMO lie mi, Olorun Oluwa! Emi ha gbodo sunmo O T’ emi t’ eru ese?
Read hymn : ALAIMO lie miALAKOSO ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe l’ owo Re, Opin gbogbo l’ ase Re.
Read hymn : ALAKOSO ti orunALEJO kan ma nkankun, Pe E wole O ti npara ‘be tip e Pe E wole.
Read hymn : ALEJO kan ma nkankunALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d’ opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l’ a o ma ko. Alleluya!
Read hymn : ALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!!AM’Oluwa iye Lo sinu ‘gbi mimo; Enit’ O wa gb’ okan wa la Ri l’ odo Jordani.
Read hymn : AM’Oluwa iyeAO ha pade l’ eti odo, T’ ese angeli ti te, ‘T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun?
Read hymn : AO ha pade l’ eti odoAO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni wa, Jek’ a tele ona ti Oluwa wa to; K’ a f’ imoran Re so agbara wa d’ otun, K’ a fi gbogbo okun wa sise t’ a o se.
Read hymn : AO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni waAPATA aiyeraiye, Se ibi isadi mi! Je ki omi on eje T’ o san lati iha Re
Read hymn : APATA aiyeraiyeAPATA aiyeraiye, Enit’ o mbe lailai, Nigbakugba t’ iji nja, ‘Bugbe wa y’o gbe je:
Read hymn : APATA aiyeraiyeAPATA wa n’ ile are, Ojiji Re bo si iyanrin, O npe awon ero ti nkoja, Lati wa si boji l’ aginju.
Read hymn : APATA wa n’ ile areARA e jek’ a jumo rin N’ ife on alafia; A ha le ma tun bere pe, O to k’ a ba f’ ija mo?
Read hymn : ARA e jek’ a jumo rinARA mi fun ‘rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sise l’ oruko Jesu, Tit’ On o tun pada, wa,
Read hymn : ARA mi fun ‘rugbin rere