LO kede igbala Jesu
LO kede igbala Jesu Gbogbo enyin onigbagbo Fun ‘rugbin Sharon ka gbogbo, Orile ede aiye yi.
Read hymn : LO kede igbala JesuLO kede igbala Jesu Gbogbo enyin onigbagbo Fun ‘rugbin Sharon ka gbogbo, Orile ede aiye yi.
Read hymn : LO kede igbala JesuAGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrereFUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘re Funrugbin l’ osan gan, ati ni ale Duro de ikore ati ‘gba ikojo A o f’ ayo pada, ru iti wole.
Read hymn : FUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘reATI gbo iro didun, Jesu le gba ni la, Ji ‘se na yi aiye ka, Jesu le gba ni la,
Read hymn : ATI gbo iro didunKRISTI fun gbogb’ aiye Ise nla naa bere Egbegberun ni gbogb’ aiye, Nfe gb’ oro ‘mo ‘Lorun
Read hymn : KRISTI fun gbogb’ aiyeILU mi, orin re, Ilu mi omnira Li emi nko; Il’ awon baba mi,
Read hymn : ILU mi, orin reOLUWA, ‘gbat’ a ngbadura Fun gbogbo enia, Gb’adura wa fun ile wa, Ile t’ a fe julo.
Read hymn : OLUWA, ‘gbat’ a ngbaduraOLUWA, jeki ore Re, To ‘lu wa pel’ agbara Re; K’ o le m’ eje ife re wa, Fun Iwo Olugbala wa.
Read hymn : OLUWA, jeki ore ReAFRIK’ ‘le wara at’ oyin, Ni orile aiye now si, T’ Olorun fun ania dudu, Fun ini re titi lailai.
Read hymn : AFRIK’ ‘le wara at’ oyinNAIJIRIA, a ki o, Orile wa owon Eya, ede le yato A duro ni ‘sokan,
Read hymn : NAIJIRIA, a ki oOLORUN orile-ede, Lat’ ibugbe Re l’ oke, Gbo ebe awon enia Re, K’ O dide si ‘gbala won.
Read hymn : OLORUN orile-edeOLUWA, Iwo l’ awa npe, A kunle siwaju ‘te Re, Nibo l’ alailera ‘ba lo, ‘Wo nikan ni nwon le kepe.
Read hymn : OLUWA, Iwo l’ awa npeORISUN lai, t’ ayo gbogbo, Ki iyin Re gba enu wa, Nigbat’ a wa sinu ‘le Re, ‘Wo-t’ ore Re buk’ odun wa.
Read hymn : ORISUN lai, t’ ayo gbogboYIN Olorun Oba wa; E gbe ohun iyin ga; Anu Re o wa titi, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waGB’ ope mi, Oluwa, Lat’ okan l’ o ti wa, Iwo t’ O gba die opo, K’yo kegan ‘more mi.
Read hymn : GB’ ope mi, OluwaA F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo;
Read hymn : A F’ ope f’ OlorunAWA nbebe fun ‘le wa, Ki Afrika ko pe; K’ Olorun Olodumare, Fi alafia fun u.
Read hymn : AWA nbebe fun ‘le waOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waAYIN O, Oluranwo wa, T’ife Re wa bakanna lai, Owo ike en’t’ o bere, Ti o si pari odun wa.
Read hymn : AYIN O, Oluranwo waOLUWA fi apa Re han, Si jek’a r’ ogo Re, Ki gbogbo wa ri ami Re, K’ o m’ okan lile ro.
Read hymn : OLUWA fi apa Re hanOJO ati akoko nlo, Nwon nsun wa s’ eti ‘boji; Awa fere dubule na, Ninu iho ‘busun wa.
Read hymn : OJO ati akoko nloBABA, je nya odun yi Si mimo fun O, N’ipokipo ti o wu Ti O fe ki nwa:
Read hymn : BABA, je nya odun yiODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo;
Read hymn : ODUN miran ti koja