NIPA ife Olugbala
NIPA ife Olugbala, Ki y’o si nkan; Oju rere Re ki pada. Ki y’o si nkan.
Read hymn : NIPA ife OlugbalaNIPA ife Olugbala, Ki y’o si nkan; Oju rere Re ki pada. Ki y’o si nkan.
Read hymn : NIPA ife OlugbalaLAIFOYA l’apa Jesu, Laifoya l’aiya Re, Labe ojij’ife Re, L’okan mi o simi.
Read hymn : LAIFOYA l’apa JesuGBA mo le ka oye mi re, Ni ibugbe l’oke; Mo dagbere f’eru gbogbo, Mo n’omije mi nu.
Read hymn : GBA mo le ka oye mi reIGBAGBO mi duro l’ori, Eje at’ododo Jesu; Nko je gbekele ohun kan, Lehin oruko nla Jesu;
Read hymn : IGBAGBO mi duro l’oriOLORUN mi bojuwo mi F’ iyanu ‘fe nla Re han mi; Ma je ki ngbere fun ‘ra mi, Tori ‘Wo si ngbero fun mi;
Read hymn : OLORUN mi bojuwo miNIGBA nwon kehin si Sion, A! opo n’ iye won; Mo seb’ Olugbala wipe, ‘Wo fe ko mi pelu?
Read hymn : NIGBA nwon kehin si SionALAFIA, li aiye ese yi, Eje Jesu nwipe, “Alafia!”
Read hymn : ALAFIA, li aiye ese yiGB’ ori soke alare, Tori ayo nbo l’ owuro, Olorun so n’nu oro Re Pe ayo ma nbo l’ owuro,
Read hymn : GB’ ori soke alareF’ORUKO Jesu s’ okan re Om’ egbe on ‘banuje; Yio fun o l’ayo oun ‘tunu Gbee wo lo s’ibi gbogbo
Read hymn : F’ORUKO Jesu s’ okan reKO si ewa nibikan ti Mo le fi we ti Krist’: Ohun t’ oku, Oluwa, ni K’ a je ‘kan pelu Re.
Read hymn : KO si ewa nibikan tiNGO fe O, Olorun Baba, Olugbala, Oba mi; Ngo fe O, ‘tori laisi Re Aiye j’ ohun kikoro.
Read hymn : NGO fe O, Olorun BabaMO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado;
Read hymn : MO ti ni Jesu l’ore