ITAN kan wa f’ awon orile
ITAN kan wa f’ awon orile, Ti yio tun okan won se, Itan otito ti o si dun, Itan alafia on ‘mole,
Read hymn : ITAN kan wa f’ awon orileITAN kan wa f’ awon orile, Ti yio tun okan won se, Itan otito ti o si dun, Itan alafia on ‘mole,
Read hymn : ITAN kan wa f’ awon orileITE anu! E je k’a lo Lati gba adura; Olorun ‘fe y’o sanu fun Awon t’o nsin nibe.
Read hymn : ITE anu! E je k’a loIWE kan wa ti kika ra, Ko soro fun enia, Ogbon ti awon t’o ka nfe, Ni okan ti o mo.
Read hymn : IWE kan wa ti kika raIWO ha nberu p’ ota yio segun? Okun su lode o sis u ju ninu? Si ferese ati ilekun sile, Jeki ‘ran orun wole.
Read hymn : IWO ha nberu p’ ota yio segunIWO imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O Kuro l’ oju iranse Re.
Read hymn : IWO imole okan miIWO low’ Enit’ ire nsan, Mo gb’ okan mi si O; N’ ibanuje at’ ise mi, Oluwa ranti mi.
Read hymn : IWO low’ Enit’ ire nsanIWO Oro Olorun, Ogbon at’ oke wa, Oto ti ki ‘yipada, Imole aiye wa;
Read hymn : IWO Oro OlorunIWO oro t’o tobi, Ninu eyit ‘a ri, Ileri ati sise Awamaridi ni:
Read hymn : IWO oro t’o tobiIWO ti gbogbo eda nsin L’ ara erupe yi, Bi O tit obi to l’aiye! B’ ogo Re ti po to!
Read hymn : IWO ti gbogbo eda nsinIWO ti okunkun Gb’ oro agbara Re, T’ o si fo lo; Gbo ti wa, a mbe O,
Read hymn : IWO ti okunkunIYE wa ni wiwo, Enit a kan mo ‘gi Iye wa nisisiyi fun o; Nje wo O elese k’ o le ri igbala, Wo Enit’ a kan mo ‘gi fun o.
Read hymn : IYE wa ni wiwo, Enit a kan mo ‘giJE, Oluwa, sin wa jeje, L’ aiye omije yi ja, Si fun wa l’ ore-ofe Re Ninu eru wa gbogbo:
Read hymn : JE, Oluwa, sin wa jeje