OLORUN fe araiye
OLORUN fe araiye, O fe tobe ge, T’ O ran Omo Re w’ aiye T’ O ku fun elses;
Read hymn : OLORUN fe araiyeOLORUN fe araiye, O fe tobe ge, T’ O ran Omo Re w’ aiye T’ O ku fun elses;
Read hymn : OLORUN fe araiyeOLORUN kutu ohun Re L’ o mu orun f’ ayo dide, Inu re dun bi omiran, Lati sare yi sanma ka.
Read hymn : OLORUN kutu ohun ReOLORUN lat’ irandiran, ‘Wo n’ isimi at’ abo wa, K’ a to da orun at’ aiye, Giga ni ife Re l’ oke.
Read hymn : OLORUN lat’ irandiranOLORUN lat’ oro d’ ale, Wakati wo l’ o dun pupo, B’ eyi t’ o pe mi wa ‘do Re Fun adua?
Read hymn : OLORUN lat’ oro d’ aleOLORUN l’ abo eni Re, Nigba iji iponju de: K’ awa to se aroye wa, A! saw o t’ On t’ iranwo Re.
Read hymn : OLORUN l’ abo eni ReOLORUN l’ odo eniti ‘Toju ife ti nwa, Iforiti gbagbo ‘reti, Ro ‘jo won lat’ oke.
Read hymn : OLORUN l’ odo enitiOLORUN mi! Olorun mi! Mo f’ ara mi fun O; Dari aisedede ji mi, Ma je ki nsako mo,
Read hymn : OLORUN mi! Olorun miOLORUN mi bojuwo mi F’ iyanu ‘fe nla Re han mi; Ma je ki ngbere fun ‘ra mi, Tori ‘Wo si ngbero fun mi;
Read hymn : OLORUN mi bojuwo miOLORUN npe, ngo ha s’ aigbo? Ngo ha s’ afe aiye d’ owon? Odun y’o ha ma rekoja K’ okan mi ma togbe sibe?
Read hymn : OLORUN npe, ngo ha s’ aigboOLORUN Olodumare, Alanu, Olore, Iwo l’ O da gbogbo aiye, Ati orun pelu.
Read hymn : OLORUN OlodumareOLORUN Olurapada, Mo ri ‘se mi nin’ oro Re, Ninu ‘gbe aiye Re nihin, Ofin f’ ara han gedegbe.
Read hymn : OLORUN OlurapadaOLORUN orile-ede, Lat’ ibugbe Re l’ oke, Gbo ebe awon enia Re, K’ O dide si ‘gbala won.
Read hymn : OLORUN orile-edeOLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba wa, Larin iji ti nja, Niwon gba t’ O wa nitsi Larin omi ti nru. 3. Iparoro ati iji, T’ o nkoja lori ‘le, Iwo ni o da gbogbo won, Nwon wa nikawo Re. 4. Nigbat’ awon Aposteli, Wa lori ‘gbi okun, Ase kan lat’ odo Re wa, Mu dake roro wa. 5. Gbati iji to buru ju, Ba nru l’ atokan wa, Oluwa ma sai ba wag be F’ alafia ba wag be. 6. Ninu wahala aiye yi, Ma se amona wa, Titi ao fi de ‘le rere, Nibi t’ ese ko si.
Read hymn : OLORUN so wa n’nu okoOLORUN ti fi Jesu se Etutu fun ese; On na l’ okan mi duro ti, Ninu igbagbo mi,
Read hymn : OLORUN ti fi Jesu seOLORUN t’ odun tr’ o koja, Iret’ eyi ti mbo; Ib’ isadi wa ni iji, At’ ile wa lailai.
Read hymn : OLORUN t’ odun tr’ o kojaOLORUN wa aiyeraiye, Ore Re ntan loke orun: Oto Re y’o la kuku ja Ti o bo ife Re loju.
Read hymn : OLORUN wa aiyeraiyeOLORUN ‘kore, te ‘ti Re, F’ ara Re han l’ ogun Sion; Ran ojise t’ o n’ itara, T’ o yara lati gb’ ase Re.
Read hymn : OLORUN ‘kore, te ‘ti ReOLORUN ‘yanu! Ona kan Ti o dabi Tire ko si; Gbogb’ ogo ore-ofe Re L’ o farahan bi Olorun.
Read hymn : OLORUN ‘yanu! Ona kanOLUGBALA, a tun fe f’ ohun kan, Yin oruko Re k’ a to tuka lo; N’ ipari sin, a dide lati yin: A ‘o si kunle fun ibukun Re.
Read hymn : OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kanOLUGBALA, gb’ ohun mi, Gb’ ohun mi, gb’ ohun mi; Mo wa sodo Re, gba mi, Nibi agbelebu.
Read hymn : OLUGBALA, gb’ ohun miOLUGBALA, lie se Re L’olote kan wole , O si f’igboiya gb’oju wo ‘Te anu Re loke.
Read hymn : OLUGBALA, lie se ReOLUGBALA mi ha gb’ ogbe? K’ Oba Ogo si ku? On ha je f’ ara Re rubo F’ eni ile b’ emi?
Read hymn : OLUGBALA mi ha gb’ ogbeOLURAPADA wa, k’ On to Dagbere ikehin, O fi Olutunu fun mi, Ti mba wa g be.
Read hymn : OLURAPADA wa, k’ On toOLUSAGUTAN ni npe mi, Kuro nin aginju ese, On p’ agutan t’ o sako lo Jina rere sinu agbo.
Read hymn : OLUSAGUTAN ni npe mi