MO fe O, Olorun, sugbon
MO fe O, Olorun, sugbon Ki se fun ere kan, Ki se nitori’ eniti Ko ba fe O yio ku,
Read hymn : MO fe O, Olorun, sugbonMO fe O, Olorun, sugbon Ki se fun ere kan, Ki se nitori’ eniti Ko ba fe O yio ku,
Read hymn : MO fe O, Olorun, sugbonIfe orun, o ti dun to! Gbawo ni ngo ri t’okan mi, Y’o kun fun kiki re? Okan mi npongbe lati mo
Read hymn : Ife orun, o ti dun toNGO feran Re, Wo odi mi; Ngo feran Re, ‘Wo ayo mi; Ngo feran Re, patapata; Ngo feran Re, tor’ ise Re,
Read hymn : NGO feran Re, Wo odi miB’ORUKO Jesu ti dun to L’ eti olugbagbo! O tan ‘banuje on ogbe, O le eru re lo.
Read hymn : B’ORUKO Jesu ti dun toOKAN mi, Oluwa ni, Jesu re ni, gb’ oro Re; Jesu nso, O mba o so, Pe, “Elese, ‘wo fe mi?”
Read hymn : OKAN mi, Oluwa niMO fe O n’gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s’ ohun ti nfun ni L’ alafia bi Tire
Read hymn : MO fe O n’gbagbogbo,IFE lo to bayi? Ohun gbogbo pari, O ti pari gbogbo ise T’ O tori re w’ aiye.
Read hymn : IFE lo to bayiMURA ebe, okan mi Jesu nfe gb’ adura re; O tip e k’ o gbadura, Nitorina yio gbo.
Read hymn : MURA ebe, okan miGBA aiye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O; Gba gbogbo akoko mi, Ki nwon kun fun iyin Re.
Read hymn : GBA aiye mi, OluwaBI agbonrin ti nmi hele, S’ ipa odo omi; Beni okan mi nmi si O, Iwo Olorun mi.
Read hymn : BI agbonrin ti nmi heleEMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole, Eyini yio j’ ogo fun mi,
Read hymn : EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio deWA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan;
Read hymn : WA, iwo isun ibukun