JESU, ise Re l’o
JESU, ise Re l’o Fi ayo s’okan mi, Nwon ni, o ti pari, Ki eru mi ko tan:
Read hymn : JESU, ise Re l’oJESU, ise Re l’o Fi ayo s’okan mi, Nwon ni, o ti pari, Ki eru mi ko tan:
Read hymn : JESU, ise Re l’oJESU, Iwo li a nwo, K’ a repo l’ oruko Re; Alade alafia, Mu k’ ija tan larin wa.
Read hymn : JESU, Iwo li a nwoJESU, kiki ironu Re, Fi ayo kun okan; Sugbon k’ a ri O l’ o dun ju, K’ a simi lodo Re.
Read hymn : JESU, kiki ironu ReJESU, nib’ eni Re pade, Nibe nwon r’ ite anu Re; Nibe nwon wa O, nwon ri O, Ibikibi n’ ile owo.
Read hymn : JESU, nib’ eni Re padeJESU, nigba aiye Re, O ko dekun wo arun; Igbe irora aisan Ko kan O k’ o bo ‘le ri.
Read hymn : JESU, nigba aiye ReJESU, Oba nla ni Sion, ‘Wo ni yio j’ amona wa; Ase Re li a gbekele, Iwo nikan l’ ao tele.
Read hymn : JESU, Oba nla ni SionJESU, O ha re ‘ra Re le Gbat’ O gb’ ara wa wo? Lati se awotan aisan, Lati l’ arun jade?
Read hymn : JESU, O ha re ‘ra Re leJESU, Oluwa or’-ofe, ‘Wo imole oju Baba, Kanga ‘mole aiyeraiye, T’ ase Re l’ okun ale lo.
Read hymn : JESU, Oluwa or’-ofeJESU, Ore ‘lese ni O; B’ elese, mo now O; Lat’ inu ekun ife Re, Oluwa, ranti mi.
Read hymn : JESU, Ore ‘lese ni OJESU, ‘ Wo Olus’-agutan, Pa agbo Re kekere mo; Gb’ awon agutan Re wonyi, Ma jekii nwon ko gbo lai.
Read hymn : JESU, ‘ Wo Olus’-agutanJESU a de l’ ojo oni Lati se ase Re, Jo masai wa si arin wa, K’ O f’ ola Re ran wa.
Read hymn : JESU a de l’ ojo oniJESU alail’ abawon, O ti f’ eje Re ra mi, Nko nani ohunkohun, Lehin agbelebu Re.
Read hymn : JESU alail’ abawon