OLUWA l’ O nso mi
OLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe?
Read hymn : OLUWA l’ O nso miOLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe?
Read hymn : OLUWA l’ O nso miOLUWA mbo aiye o mi Oke y’o sidi n’ipo won; At ‘irawo oju orun, Y’o mu imole won kuro.
Read hymn : OLUWA mbo aiye o miOLUWA mi, mo kepe O Ngo ku b’ O ko ran mi lowo; Jo, fi igbala Re fun mi Gbi mi bi mo ti ri.
Read hymn : OLUWA mi, mo kepe OOLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l’ emi o mo, L’ oro, l’ ero ati n’ ise.
Read hymn : OLUWA mi, mo njade loOLUWA mo gb’ ohun Re, Ti npe mi wa ‘do Re, Fun ‘wenumo n’nu eje Re T’o san ni Kalfari.
Read hymn : OLUWA mo gb’ ohun ReOLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni ObaOLUWA orun at’ aiye! Jesu, Omo ninu ara! Emi Mimo fun ‘toju wa! E gbo, ki E si gb’ eje wa.
Read hymn : OLUWA orun at’ aiyeOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin.
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funOLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re.
Read hymn : OLUWA sokaleOLUWA t’ o mo julo, K’ a wole l’ oruko Re; Ife Re ki ye titi, Kab’yesi Oba rere.
Read hymn : OLUWA t’ o mo juloOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiOLUWA wa mimo, Ti ogun orun nyin, Masai gbo wa; Kerubu, Serafu,
Read hymn : OLUWA wa mimoOLUWA wow a l’ ese Re Otosi elese; Gege bi eniti nbebe, A wa ni ase Re.
Read hymn : OLUWA wow a l’ ese ReOMO Olorun nlo s’ ogun Lati gb’ ade Oba: Opagun Re si nfe, lele, Tal’ o s’ om-ogun Re?
Read hymn : OMO Olorun nlo s’ ogunOM’-OGUN Krist’ dide Mu ‘hamora nyin wo; Mu ‘pa t’ Olorun fi fun nyin, Nipa ti Omo Re.
Read hymn : OM’-OGUN Krist’ dide.OM’ Olorun, a ko ri O, ‘Gbat’ O wa s’ aiye iku yi; Awa ko ibugbe Re, Ni Nasareti ti a gan;
Read hymn : OM’ Olorun, a ko ri OONA ara l’ Olorun wa Ngba sise Re l’ aiye; A nri ‘pase Re lor’ okun, O ngun igbi l’ esin.
Read hymn : ONA ara l’ Olorun waONA Re, Oluwa, B’ o ti wu k’ o su to, Masai f’ owo ‘tun Re to mi, Yan ipa mi fun mi.
Read hymn : ONA Re, OluwaONIGBAGBO, e bu s’ ayo! Ojo nla l’ eyi fun wa; K’ orun f’ ayo korin kikan, K’ igbo at’ odan gberin.
Read hymn : ONIGBAGBO, e bu s’ ayoONIGBAGBO, e wo Oluwa nyin n’nu ‘se, A ri s inu okun ‘rora, T’ o b’ okan Re mo ‘le.
Read hymn : ONIGBAGBO, e woONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu!
Read hymn : ONISEGUN nla wa nihinONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu!
Read hymn : ONISEGUN nla wa nihinONTO mi lo iro ‘bukun, Oro t’ orun tu mi ninu, Ohun ti o wu kemi se Sibe Olorun nto mi lo.
Read hymn : ONTO mi lo iro ‘bukunOPARI! – l’ Olugbala ke, O te ori ba, O si ku; “O pari!” – ire – ije pin, O ti jagun, O si segun.
Read hymn : OPARI! – l’ Olugbala ke