OPO ikan omi
OPO ikan omi, Yanrin kekeke; Wonyi l’ o d’ okun nla At’ ile aiye.
Read hymn : OPO ikan omiOPO ikan omi, Yanrin kekeke; Wonyi l’ o d’ okun nla At’ ile aiye.
Read hymn : OPO ikan omiORE-OFE! Ohun Adun ni l’ eti wa; Gbongbon re yio gba orun kan, Aiye o gbo pelu.
Read hymn : ORE-OFE! OhunORE kan mbe fun omode Ninu awon orun; Ore ti ki yipada, T’ ife Re ko le ku;
Read hymn : ORE kan mbe fun omodeORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po, Ife nla ti ko le sa, Bi mo tile s’ aito, S’ife Re yi ni mo ti se;
Read hymn : ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re poKristi lori agbelebu, Ti san gbogbo igbese mi, Ko si ohun miran t’ o le, Ma alafia didun na wa.
Read hymn : ORIN t’o dun wa s’okan miORISUN lai, t’ ayo gbogbo, Ki iyin Re gba enu wa, Nigbat’ a wa sinu ‘le Re, ‘Wo-t’ ore Re buk’ odun wa.
Read hymn : ORISUN lai, t’ ayo gbogboORO die fun Jesu; Ore otito ni; Wa tu okan wa ninu Ohun t’o se fun o.
Read hymn : ORO die fun JesuORU bu koja tan Osan ku si dede: Iboju fere ya T’o bo Olugbala;
Read hymn : ORU bu koja tanORUN, korin! Aiye, yo! Angeli at’ enia, E yi ka b’ O ti ndide, E gbe ‘yin Jesu nyin ga.
Read hymn : ORUN, korin! Aiye, yoORUN si nyara wo, Ojo nku lo; K’ ife ko ji dide, K’ o rubo asale.
Read hymn : ORUN si nyara woOSE, ose rere, Iwo ojo ‘simi; O ye k’ a fi ojo kan, Fun Olorun rere;
Read hymn : OSE, ose rereOSE, ose t’ a nreti A ki o pe “Ma wole,” Iwo ni idunnu wa, A kio s’ ole ninu re.
Read hymn : OSE, ose t’ a nret“O SUN,” ni Jesu wi Nipa ti Lasaru, Enit’ o ku, ti a ti san, T’ a ti te s’ iboji.
Read hymn : O SUN,” ni Jesu wiO TI to Jesu f’ agbara ‘wenumo? A we o nin’ ej Odagutan? Iwo ha ngbekele ore-ofe Re? A we o nin’ ej Odagutan?
Read hymn : O TI to Jesu f’ agbara ‘wenumoOTUN ife l’ o nfarahan, Bi a ti nji l’ ojojumo, Lat’ inu orun at’ okun, A ji s’ agbara at’ ero.
Read hymn : OTUN ife l’ o nfarahanOWO at’ Alabukunfun Ni ile t’ o jewo Jesu, Okan at’ ile na l’ ayo Nibiti Olugbala wo.
Read hymn : OWO at’ AlabukunfunOWO l’ eni ororo Re, L’ ojise oro mimo Re Ipo eni owo l’ o wa, Jek a f’ iyin at’ ola fun.
Read hymn : OWO l’ eni ororo RePADA asako s’ ile re, Baba re l’ O npe o; Ma se alarinkiri mo, N’nu ese at’ osi.
Read hymn : PADA asako s’ ile rePARADISE! Paradise! Tani ko fe simi? Tani ko fe ‘le ayo na, Ile alabukun;
Read hymn : PARADISE! Paradise!PELU iwa mimo, b’ Oluwa s’ oro Be ‘nu Re n’ gbagbogbo je onje iye, B’ onigbagbo s’ ore, Ran ailera lowo; Ma gbagbe nigbakan, wa ibukun Re.
Read hymn : PELU iwa mimo, b’ Oluwa s’ oroPIPE n’ ise ‘gbala, Lekan o pari lai; Pipe ni ododo, Ti o bo elese:
Read hymn : PIPE n’ ise ‘gbalaRANSE Olorun seun; Simi n’nu lala re; Iwo ti ja, o si segun; Bo s’ ayo Baba re,
Read hymn : RANSE Olorun seunSA dake, okan mi, Oluwa re wa n’be, Enit’ o ti se ileri, Yio fe mu u se.
Read hymn : SA dake, okan miSAJU wan so, Olorun, Fere ogun ti ro; Ninu papa isegun, N’ago Re l’ao ma gbe
Read hymn : SAJU wan so, Olorun