← Back to the hymnbook
Yoruba Baptist Hymns No. 506

O SUN,” ni Jesu wi

Read. Sing. Share.

Verse 1

“O SUN,” ni Jesu wi
Nipa ti Lasaru,
Enit’ o ku, ti a ti san,
T’ a ti te s’ iboji.

Verse 2

Oku ojo merin,
L’ oju Jesu, sun ni,
On l’ Ajinde ati Iye
F’ awon t’ o gba A gbo.

Verse 3

Ore Je ski ku,
Nwon a ma parade,
Kuro ni kokoro ile,
S’ ohun ti nfo l’ oke.

Verse 4

Sun, ara, olufe,
Jesu duro ti o,
Ma foya, O ti se ‘leri,
Ajinde f’ eni Re.

Verse 5

O fere gb’ ohun na,
Lat’ oju orun re,
Ohun didun Jesu ti yio
Pe o si isoji.

Verse 6

A ko ni b’ ara je
Bi alain’ ireti,
O d’ owuro l’ a le ki o,
Sun re, ara, sun re.

Verse 7

Awa pelu yio sun
Li akoko ti wa;
A! k’ ile mo ba gbogbo wa
L’ese Olugbala.

Conversation 0 comments

Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.

Share anonymously

No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.

Where are you joining from?

Your city and country appear beside your anonymous comment after review.

Form verification is provided by Cloudflare Turnstile.

Sign in to keep track of replies

Report a lyric correction

Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.

Form verification is provided by Cloudflare Turnstile.Your details are used to respond to this submission.
Support the archive