TORI Mi at’ ihinrere
TORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo; Nwon nso t’ibi tiya t’iku, Ife etutu nla Re; Nwon ka o
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrere643 hymns
TORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo; Nwon nso t’ibi tiya t’iku, Ife etutu nla Re; Nwon ka o
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrereT’ IFE Jesu t’o wa mi, Gbat’ mo nu n’ ese; T’ ore ofe t’ o mu mi Pada bo sin’ agbo; Ti giga jinle anu, To jin ju okun lo, To si ga j’ awon,
Read hymn : T’ IFE Jesu t’o wa miT’ OLORUN n’ ijoba gbogbo Oril-ede, e korin ‘yin: E so t’ ipa Re to tobi; Ola Re y’o m’ orin yin dun. O nsan ara lat’ orun wa; Oruko Re nro
Read hymn : T’ OLORUN n’ ijoba gbogboWA ba mi gbe! ale fere le tan, Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe, Bi oluranlowo miran ba ye, Iranwo alaini, wa ba mi gbe. Ojo aiye mi nsare lo s
Read hymn : WA ba mi gbe! ale fere le tanWA Emi Mimo, wa, Pelu ipa t’ orun, Si ran ninu anu Re nla Sor’ okan okun wa. Yo okan lile yi; Te ‘fe agidi ba; Bori gbogbo ifekufe, K’ O si
Read hymn : WA Emi Mimo, waWA enyin oloto L’ ayo at’ isegun Wa kalo, wa kalo si Betlehem; Wa kalo wo o! Oba awon Angeli! E wa kalo juba Re, E wa k’ a lo juba Kristi Ol
Read hymn : WA enyin olotoWA k’ a da m’ awon ore wa Ti nwon ti jere na; N’ ife k’ a f’ okan ba won lo S’ ode orun lohun. K’ awon t’ aiye d’ orin won mo, T’ awon t’ o
Read hymn : WA k’ a da m’ awon ore waWA rohin Re yika K’o si korin ogo; Alagbara ni Oluwa Oba gbogbo aiye. Wa, wole n’ ite Re, Wa teriba fun U; Ise owo Re l’ awa se Oro Re l’ o
Read hymn : WA rohin Re yikaWA sodo Jesu, mase duro, N’ oro Re l’ O ti f’ ona han wa, O duro li arin wa loni, O nwi jeje pe, “Wa.” Ipade wa yio je ayo, Gb’ okan wa ba
Read hymn : WA sodo Jesu, mase duro“WA sodo Mi, alare Ngo fun nyin n’ isimi.” A! ohun didun Jesu, Ti o p’ elese wa, O nso ti ore ofe, Ati t’ Alafia, Ti ayo ti ko l’opin, T’ife
Read hymn : WA sodo Mi, alareWA ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu nisin! Nisin wa’ do Jesu! Wa ‘do Jesu nisin! Yio gba o la! Etc Sa gba A gbo! Etc O le gba o! Etc.
Read hymn : WA ‘do Jesu!WA, Emi ‘re, ‘Dada orun Pelu itunu lat’ oke; S’ alabo at’ Oluto wa, To ero at’ isise wa. F’ imole otito han wa, Mu k’ a mo, k’ a yan ona Re
Read hymn : WA, Emi ‘re, ‘Dada orunWA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de; Olorun Eleda wa L’ O ti pese f’ aini wa; Wa k’a re ‘le Olorun
Read hymn : WA, enyin olope, waWA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan; Oluwa, ko mi l’ orun na T’ ogun orun nko l’ oke; Je ki
Read hymn : WA, iwo isun ibukunWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de. Ife rere Re, jek’ a f’ ayo mu se, K’ a malo ebun wa, Ni
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waWA, Jesu fi ara han; Wa, je k’okan wa mo O: Wa, mu gbogb’ okan gbona, Wa, bukun wa k’a to lo. Wa, f’ aiya wa n’ isimi, Wa, k’ a d’ alabukun
Read hymn : WA, Jesu fi ara hanWA, ma sise, Tani gbodo s’ole ninu oko, Gbati gbogbo enia nkore jo? Kaluku ni Baba pase fun pe, – “Sise loni.” Wa, ma sise, Gba ‘pe giga ti
Read hymn : WA, ma siseWA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun, Krist, t’ O jinde n’ipa, Krist, t’ O de nyin l’ ade, On ni k’e yin. E o awon
Read hymn : WA, obirin, e koWA, Oluwa, l’ anu tun wa, Pelu ‘pa ‘p’ okan da, Ongbe ojo np’ oko Sion, Masai ro s’ ori re. Okan wa kun f’ are kikan, Lati ri b’ elese, Ti
Read hymn : WA, Oluwa, l’ anu tun waWALEJO kan lenu ona: O nkankun je, O ti nkan ri; O ti duro pe, O nduro; Ko s’ ore t’ o je ba lo be. ‘Duro ife! a, O nduro, Okan Re yo, owo
Read hymn : WALEJO kan lenu onaWO b’ ikore tip o L’ otun l’ osi wa, Alagbase kere L’ ogba Oluwa, Enyin omo ‘bile, Dide s’ igbala Awon omo ‘ya wa T’ o wa l’ okunkun. Wo b’
Read hymn : WO b’ ikore tip oWO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo. To ‘sise mi: bi ona ti jin to, Nki o bere; ‘sise kan t
Read hymn : WO Imole! larin okun aiyeWO kakiri f’ enit’ o s’ alaini, R’ enia lowo loni! Bi ‘ranlowo na si tile kere, R’ enia lowo loni! R’ enia lowo loni, Enia lona aiye yi; Mu
Read hymn : WO kakiri f’ enit’ o s’ alainiWO oju sanma ohun ni. Wo lila orun oro. Ji l’ oju orun, okan mi, Dide k’ o si ma sora; Olugbala Tun npada bow a s’ aiye. O pe ti mo ti nret
Read hymn : WO oju sanma ohun ni