OTUN ife l’ o nfarahan
OTUN ife l’ o nfarahan, Bi a ti nji l’ ojojumo, Lat’ inu orun at’ okun, A ji s’ agbara at’ ero. Otun anu l’ ojojumo L’o nra yi wa ka n’ oku
Read hymn : OTUN ife l’ o nfarahan643 hymns
OTUN ife l’ o nfarahan, Bi a ti nji l’ ojojumo, Lat’ inu orun at’ okun, A ji s’ agbara at’ ero. Otun anu l’ ojojumo L’o nra yi wa ka n’ oku
Read hymn : OTUN ife l’ o nfarahanOWO at’ Alabukunfun Ni ile t’ o jewo Jesu, Okan at’ ile na l’ ayo Nibiti Olugbala wo. Gb’ ori s’ oke, ilekun nla, E wo, Oba ogo duro: Oba a
Read hymn : OWO at’ AlabukunfunOWO l’ eni ororo Re, L’ ojise oro mimo Re Ipo eni owo l’ o wa, Jek a f’ iyin at’ ola fun. Ipo elegbe n’ ipo re, Aso ti ko fe abawon, Jek’ a
Read hymn : OWO l’ eni ororo RePADA asako s’ ile re, Baba re l’ O npe o; Ma se alarinkiri mo, N’nu ese at’ osi. Pada, pada, pada. Pada asako s’ ile re, Jesu l’ O sa npe o
Read hymn : PADA asako s’ ile rePARADISE! Paradise! Tani ko fe simi? Tani ko fe ‘le ayo na, Ile alabukun; Nib’ awon oloto Wa lai ninu’ mole, Nwon nyo nigbagbogbo, Niwaju Ol
Read hymn : PARADISE! Paradise!PELU iwa mimo, b’ Oluwa s’ oro Be ‘nu Re n’ gbagbogbo je onje iye, B’ onigbagbo s’ ore, Ran ailera lowo; Ma gbagbe nigbakan, wa ibukun Re.
Read hymn : PELU iwa mimo, b’ Oluwa s’ oroPIPE n’ ise ‘gbala, Lekan o pari lai; Pipe ni ododo, Ti o bo elese: Ife t’ o bukun wa l’ aiye, O nsan l’ ofe nisisiyi. Irubo to koja, A ke
Read hymn : PIPE n’ ise ‘gbalaRANSE Olorun seun; Simi n’nu lala re; Iwo ti ja, o si segun; Bo s’ ayo Baba re, Ohun na de l’ oru, O dide lati gbo; Ofa iku si wo l’ ara, O
Read hymn : RANSE Olorun seunSA dake, okan mi, Oluwa re wa n’be, Enit’ o ti se ileri, Yio fe mu u se. On ti fa o lowo, O mu o de ‘hinyi, Yio pa o mo la ewu ja, Tit’ igb
Read hymn : SA dake, okan miSAJU wan so, Olorun, Fere ogun ti ro; Ninu papa isegun, N’ago Re l’ao ma gbe Anu re fun wa l’okun N’ipalemo f’ ogun na A si wa nkorin ‘segun
Read hymn : SAJU wan so, OlorunSI pepe Oluwa, Mo mu ‘banuje wa; ‘Wo ki f’ anu tewogba Ohun alaiye yi? Kristi Odagutan Ni igbagbo mi now; ‘Wo le ko ‘hun alaiye yi? ‘Wo o g
Read hymn : SI pepe OluwaSIMI le Oluwa -e gbo Orin duru orun – Simi le ife ailopin, Si duro je, Simi, iwo oko t’ o gba Iyawo re loni; Ninu Jesu, ‘yawo re ni Titi ai
Read hymn : SIMI le Oluwa -e gboSION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan segbe s’ inu okunkun. Je gbogb’ eda gb
Read hymn : SION yara, k’ o je ise giga reSISE tori oru mbo ! Sise li owuro; Sise nigba iri nse, sise n’nu ‘tanna; Sise ki osan to pon, sise nigb’ orun nran, Sise tori oru mbo ! ‘gb
Read hymn : SISE tori oru mbo ! Sise li owuroSISE, akoko nlo, Se tokantokan; Sise, okan nsegbe, Sise, oru mbo, N’nu ogba Oluwa Lo sise loni, Ma duro laise nkan, Mase jafara. N’nu ‘pe t
Read hymn : SISE, akoko nloSO itan kanna fun mi, T’ ohun ni t’ a ko ri; Ti Jesu on ogo Re, Ti Jesu En ‘ ife, So itan kanna fun mi, B’ o ba ti so f’ ewe, ‘Tor’ alailera
Read hymn : SO itan kanna fun miSUNM’ odo wa, Emmanuel, Wa’ra Israel pada, T’ on sofo li oko eru Titi Jesu y’o tun pada. E yo, e yo, Emmanuel Y’ o wa s’ odo wa Israel. Wa,
Read hymn : SUNM’ odo wa, EmmanuelTAL’ awon wonyi b’ iranwo, Niwaju ‘te Olorun? Gbogbo nwon de ade wura, Egbe ogo wo l’ eyi? Gbo! nwon nko, Alleluya, Nwon nf’ iyin fun Oba wo
Read hymn : TAL’ awon wonyi b’ iranwo,TAL’ o mo adun isimi, B’ o ye l’ awon t’ o ni, Ti se ‘pin awon ayanfe, Nipa eje Jesu? Tal’ o le so ‘jinle ayo, T’ o nsun li okan won, Lat’
Read hymn : TAL’ o mo adun isimiTIRE lailai l’ awa se, Baba Olorun ife; Je k’ a je Tire titi, L’ aiye yi, ati lailai. Tire lailai l’ awa se, Ma toju wa l’ aiye yi: ‘Wo iye
Read hymn : TIRE lailai l’ awa seTIRE l’ awa Kristi, Titi aiyeraiye, A fe fi gbogbo okan wa Fun O patapata. Ao ro mo O sibe, Pelu itara nla; B’ opo nfa wa lodo Jesu, Ma je
Read hymn : TIRE l’ awa KristiTIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re, O nso ife Re si mi: Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O. Fa mi mora, mora, Oluwa, Sib’ a
Read hymn : TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun ReTIRE l’ ola Baba, O wa n’ ikawo Re; B’ ojum’ ola si mo ba ni, Nipa ase Re ni. Akoko yi nfo lo, O ngbe emi wa lo; Oluwa, mu ‘ranse Re gbon,
Read hymn : TIRE l’ ola BabaTO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni, Nipa ‘fe Re orun, To nwon, Baba si O, To nwon, Baba si O, To nwon si O. ‘Gbat
Read hymn : TO nwon, Baba si O