OLUWA ni Oba
OLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi; Gb’ okan at’ ohun nyin s’ oke. “E yo,” mo sit un wi “E yo.” Olugbala j
Read hymn : OLUWA ni Oba643 hymns
OLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi; Gb’ okan at’ ohun nyin s’ oke. “E yo,” mo sit un wi “E yo.” Olugbala j
Read hymn : OLUWA ni ObaOLUWA orun at’ aiye! Jesu, Omo ninu ara! Emi Mimo fun ‘toju wa! E gbo, ki E si gb’ eje wa. A gba O, Jesu ti a pa, A gba ‘Wo t’ O r’ oke oru
Read hymn : OLUWA orun at’ aiyeOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin. Oluwa po! Titobi Re si l’ o
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funOLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re. B’ o ti je ‘fe wa to Lati ri ayo won, Gbogbo ife wa si dapo, Lati t
Read hymn : OLUWA sokaleOLUWA t’ o mo julo, K’ a wole l’ oruko Re; Ife Re ki ye titi, Kab’yesi Oba rere. B’ a ti je alaiye to, Sibe O ngbo orin wa, Iyin t’ o ye l’
Read hymn : OLUWA t’ o mo juloOLUWA wa mimo, Ti ogun orun nyin, Masai gbo wa; Kerubu, Serafu, At’ awon angeli, S’ odo R ni nwon nmu Iyin nwon wa. Fun oro Re n’ ipa, Buku
Read hymn : OLUWA wa mimoOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin. L’ osan l’ oru, n’ ile, l’ ayo, Oluwa wa
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiOLUWA wow a l’ ese Re Otosi elese; Gege bi eniti nbebe, A wa ni ase Re. A wa mbebe f’ awon ‘mo wa, T’ Iwo ti fi fun wa; Tal’ a o to n’ igba
Read hymn : OLUWA wow a l’ ese ReOLUWA, a wa ‘do, Re, L’ese Re l’ a kunle si; A! ma kegan ebe wa, A o wa O lasan bi? L’ ona ti O yan fun wa, L’ a nwa O lowolowo; Oluwa, a k
Read hymn : OLUWA, a wa ‘do, Re,OLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je. Lojukanna bi a ti mi, Eso ese nru fun iku; Ofin
Read hymn : OLUWA, alaimo l’ emiOLUWA, Baba orun, B’ oju woo mo-‘do Re Ti nro t’ igbe aiye re, Ati ipo re si O. Mo n’ igbgbo si Jesu, Si agbara iku Re, S’ ajinde Re, apere
Read hymn : OLUWA, Baba orunOLUWA, bawo l’ okan mi Ti bale lekan ri; Mo wa laye laisi ofin, Mo seb’ ese mi ku. Ireti duro sinsin, Sugbon nigb’ ofin de, Pelu imole t’ o
Read hymn : OLUWA, bawo l’ okan miOLUWA, b’ agbowode ni, Mo gb’ okan mi le O; Oluwa, f’ ore-ofe wi, K’ O se anu fun mi. Mo lu aiduro aiya mi, Ekun at’ irora; K’ Ogb’ okan mi
Read hymn : OLUWA, b’ agbowode niOLUWA, iji nfe s’ oke! Igbi omi nru s’ oke! Oju orun pelu su dudu, ‘Ranlowo ko si n’ tosi; ‘Wo ko bere bi a segbe? Ba o n’ Iwo se le sun? Gb
Read hymn : OLUWA, iji nfe s’ okeOLUWA, isimi Re dun; Sugbon t’ oke ju ti aiye lo; Sibe pelu ‘reti ayo Li okan ongbe wa nsare. Ko si are, ko si ise, Ese, iku ki y’o de ‘be
Read hymn : OLUWA, isimi Re dunOLUWA, Iwo l’ awa npe, A kunle siwaju ‘te Re, Nibo l’ alailera ‘ba lo, ‘Wo nikan ni nwon le kepe. Oluwa, awa yipada S’ odo Re t’ a ti ko si
Read hymn : OLUWA, Iwo l’ awa npeOLUWA, jeki ore Re, To ‘lu wa pel’ agbara Re; K’ o le m’ eje ife re wa, Fun Iwo Olugbala wa. Ki gbogbo ‘le Olorun da Orin ‘segun t’ iyin mi
Read hymn : OLUWA, jeki ore ReOLUWA, ki s’agbara mi Bi mo ye, bi mo ku; Lati sin O ni ipin mi, Iwo ni si fun ni. B’emi mi gun emi o yo Lati sin O titi, B’ o si kuru, em’
Read hymn : OLUWA, ki s’agbara miOLUWA, ma m’ oju kuro Lodo emi t’ o ny’ ile, Ti nsokun ese aiye mi, N’ ite anu ife Re. Ma ba mi lo sinu ‘dajo, Bi ese mi ti po to: Nitori m
Read hymn : OLUWA, ma m’ oju kuroOLUWA, mo gbo pe Iwo Nro ojo ‘bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s’ ori mi. An’ emi! Ro ojo re s’ ori mi! Ma koja Baba Olore, Bi ese
Read hymn : OLUWA, mo gbo pe IwoOLUWA, nje ‘dariji Re Yio gb’ eni bi emi? Nje, O gbe ese mi kuro O f’ erin bukun mi? Nje fun mi l’ O r’ agbelebu Lai nani egan Re? Jesu, o
Read hymn : OLUWA, nje ‘dariji ReOLUWA, Ob’ Alase, A wole ni ese Re; Gbo igbe itara wa, Bi O ba r’ oju, ao ku. O to, bi oko iku Ba gun, okan ebi wa, O to, bi ategun Re F’ i
Read hymn : OLUWA, Ob’ AlaseOLUWA, ojo t’ O fun wa pin Okunkun si de l’ ase Re ‘Wo l’ a korin owuro wa si, Iyin Re y’o m’ale wa dun. A dupe ti Ijo Re ko nsun, B’ aiye
Read hymn : OLUWA, ojo t’ O fun wa pinOLUWA, sanu, dariji; Da okan t’o yipada si; Ki sip e anu Re tobi Elese ko le ro mo O? Ese mi po, sugbon ko le Ju agbara ore Re lo; Titobi R
Read hymn : OLUWA, sanu, dariji