OLORUN orile-ede
OLORUN orile-ede, Lat’ ibugbe Re l’ oke, Gbo ebe awon enia Re, K’ O dide si ‘gbala won. Bi ese t’ o b’ okan wa je, Nf’ ohun rara ke f’ esan
Read hymn : OLORUN orile-ede643 hymns
OLORUN orile-ede, Lat’ ibugbe Re l’ oke, Gbo ebe awon enia Re, K’ O dide si ‘gbala won. Bi ese t’ o b’ okan wa je, Nf’ ohun rara ke f’ esan
Read hymn : OLORUN orile-edeOLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba wa, Larin iji ti nja, Niwon gba t’ O wa
Read hymn : OLORUN so wa n’nu okoOLORUN ti fi Jesu se Etutu fun ese; On na l’ okan mi duro ti, Ninu igbagbo mi, Olorun si ni iyonu Si eje Omo Re; Omo si ti mu eje na Wo ibi
Read hymn : OLORUN ti fi Jesu seOLORUN t’ odun tr’ o koja, Iret’ eyi ti mbo; Ib’ isadi wa ni iji, At’ ile wa lailai. Labe ojiji ite Re L’ awon enia Re ngbe! Tito l’ apa Re
Read hymn : OLORUN t’ odun tr’ o kojaOLORUN wa aiyeraiye, Ore Re ntan loke orun: Oto Re y’o la kuku ja Ti o bo ife Re loju. Ore Re duro titi lai, Bi oke ti f’ idi mule; Ogbon n
Read hymn : OLORUN wa aiyeraiyeOLORUN ‘kore, te ‘ti Re, F’ ara Re han l’ ogun Sion; Ran ojise t’ o n’ itara, T’ o yara lati gb’ ase Re. Wo wa l’ oju Oluwa wa, Ikore pon,
Read hymn : OLORUN ‘kore, te ‘ti ReOLORUN ‘yanu! Ona kan Ti o dabi Tire ko si; Gbogb’ ogo ore-ofe Re L’ o farahan bi Olorun. Tal’ Olorun ti dariji, Ore tal’ o po bi Tire? N’
Read hymn : OLORUN ‘yanu! Ona kanOLORUN! Kini mo ri yi! Opin de f’ohun gbogbo! Onidajo araiye yo, O gunwa n’ite ‘dajo Ipe dun, iboji sit u, Gbogbo awon oku sile; Mura, lo ko
Read hymn : OLORUN! Kini mo ri yiOLUGBALA mi ha gb’ ogbe? K’ Oba Ogo si ku? On ha je f’ ara Re rubo F’ eni ile b’ emi? Iha se ese ti mo da L’ o gbe ko sor’ igi? Anu at’ ore
Read hymn : OLUGBALA mi ha gb’ ogbeOLUGBALA, a tun fe f’ ohun kan, Yin oruko Re k’ a to tuka lo; N’ ipari sin, a dide lati yin: A ‘o si kunle fun ibukun Re. F’ Alafia fun wa,
Read hymn : OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kanOLUGBALA, gb’ ohun mi, Gb’ ohun mi, gb’ ohun mi; Mo wa sodo Re, gba mi, Nibi agbelebu. Emi se, sugbon O ku, Iwo ku, Iwo ku; Fi anu Re pa mi
Read hymn : OLUGBALA, gb’ ohun miOLUGBALA, lie se Re L’olote kan wole , O si f’igboiya gb’oju wo ‘Te anu Re loke. Bi omije aro ba to San ‘gbese ti mo je, Ekun ‘ba ma san li
Read hymn : OLUGBALA, lie se ReOLURAPADA wa, k’ On to Dagbere ikehin, O fi Olutunu fun mi, Ti mba wa g be. O wa ni awo adada, O na iye bow a; O tan ‘fe on alafia S’ ori a
Read hymn : OLURAPADA wa, k’ On toOLUWA alafia wa L’ O pase t’ odun yipo; Awa omo Re wa dupe F’ odun titun t’ a bere. Yin Oluwa! Oba nla t’ O da wa si. A dupe fun ipamo wa N
Read hymn : OLUWA alafia waOLUWA at’ ‘igbala wa, L’ o ko wa jo l’ ale oni, Je ka gbe Ebeneser ro; Odun t’ a ti la koja yi, Ni on f’ore Re de l’ade Otun l’ anu Re l’ ow
Read hymn : OLUWA at’ ‘igbala waOLUWA fi apa Re han, Si jek’a r’ ogo Re, Ki gbogbo wa ri ami Re, K’ o m’ okan lile ro. K’ anu yow a ninu ebi, Gbogb’ ese t’ a ati da, Ki od
Read hymn : OLUWA fi apa Re hanOLUWA ib’ isadi mi, ‘Wo ni mo gbekele; Oro Re gba mi n’ iyanju, Emi erupe ‘le. Awiye ko si l’ enu mi, Ko si ebe miran; O to pe Olugbala ku,
Read hymn : OLUWA ib’ isadi mi“OLUWA ji loto:” O wa ko ni ku mo, O wa lati be f’ elese, Ti o ru egan won. “Oluwa ji loto:” Esu so tire nu: Awon t’ a ra ji pelu Re, Lati
Read hymn : OLUWA ji lotoOLUWA l’ atilehin mi, Kini ‘ba te mi ri? Eniti O da aiye ro, T’ O ta sanma l’ aso. Ki nku, nigbati Jesu ji Kuro larin iku? Okan mi ti gba ‘
Read hymn : OLUWA l’ atilehin miOLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe? O sin mi lo sibi Ti papa orun nhu, Sibit’ omi ‘ye nsan j
Read hymn : OLUWA l’ O nso miOLUWA mbo aiye o mi Oke y’o sidi n’ipo won; At ‘irawo oju orun, Y’o mu imole won kuro. Oluwa mbo; bakanna ko; Bi o ti wa n’ irele ri, Odo a
Read hymn : OLUWA mbo aiye o miOLUWA mi, mo kepe O Ngo ku b’ O ko ran mi lowo; Jo, fi igbala Re fun mi Gbi mi bi mo ti ri. Gba mi bi mo ti ri (2) Kristi ku fun mi l’ebe m
Read hymn : OLUWA mi, mo kepe OOLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l’ emi o mo, L’ oro, l’ ero ati n’ ise. Ise t’ O yan mi l’ anu Re Je ki nle se tayotay
Read hymn : OLUWA mi, mo njade loOLUWA mo gb’ ohun Re, Ti npe mi wa ‘do Re, Fun ‘wenumo n’nu eje Re T’o san ni Kalfari. Mo Mbo Oluwa, Mo Mbo s’ odo Re We mi ninu eje Re T’ o
Read hymn : OLUWA mo gb’ ohun Re