ODUN miran ti koja
ODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo; Anu l’ O fid a wa si, A ha lo anu na bi? K’ a bi ‘ra wa b’ a
Read hymn : ODUN miran ti koja643 hymns
ODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo; Anu l’ O fid a wa si, A ha lo anu na bi? K’ a bi ‘ra wa b’ a
Read hymn : ODUN miran ti kojaOGABJO gan: l’ oke Olif’ Awon irawo si ti wo; Oganjo gan: nisisyi Jesu nikan ngbadura l’ ogba. Ogbanjo gan: l’ ais’ enikan, Jesu nikan ba e
Read hymn : OGABJO gan: l’ oke OlifOGO f’ Olorun l’ ale yi Fun gbogbo ore imole, So mi, Oba awon oba Labe ojiji iye Re. Oluwa, f’ ese mi ji mi, Nitori Omo Re loni; K’ emi le
Read hymn : OGO f’ Olorun l’ ale yiOG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu, Ona Re si yato; Ko si j’ ohun t’ o wu eda, Lati fi iyin fun. Ibukun ni f’ awon t’ a fun L’ oye lati mo pe, Olorun
Read hymn : OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanuOHUN ipe kan ti, oke petele wa, S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist, Oke gba orin na, gege b’o ti ndun lo, T’ olotito, ‘lotito, A! ‘lotito
Read hymn : OHUN ipe kan ti, oke petele waOHUN ogo Re l’ a nrohin, Sion’ ti Olorun wa; Oro Enit’ a ko le ye, Se o ye fun ‘bugbe Re, L’ ori apat’ aiyeraiye, Kini le mi ‘simi re? A f’
Read hymn : OHUN ogo Re l’ a nrohinOHUN tin dun l’ aginju, Ohun alore ni, Gbo b’ o tin dun rara pe, “E ronupiwada.” Ohun na ko ha dun to Ipe na ko kan o? Kil o se, arakunrin,
Read hymn : OHUN tin dun l’ aginjuOJISE Krist’, dide, E mura fun ‘se na, Iri ‘bukun lat’ orun wa Ti se s’ ori ile. Lo toju alaisan, At’ awon ti nsofo, Lo s’ odo awon ti nron
Read hymn : OJISE Krist’, dideOJO ayo l’ ojo ti mo Yan O, ‘Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’ o si s’ ayo re kakiri Ojo nla l’ ojo na, Ti Jesu we ese mi nu! O ko m
Read hymn : OJO ayo l’ ojo ti moOJO ayo nlanla na de, Eyit’ araiye ti nreti; Nigbat’ Olugbala w’ aiye, Nigbat’ a bi ninu ara. Olusagutan ni papa, Bi nwon ti nso agutan won
Read hymn : OJO ayo nlanla na deOJO ibukun yio sir o!” Eyi n’ ileri ife; A o ni itura didun Lat’ odo Olugbala Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe; Iri anu wa yi wa ka, sugbon o
Read hymn : OJO ibukun yio sir oOJO mefa t’ ise koja, Okan t’ isimi si bere; Pada okan mi wa ‘simi, Yo s’ ojo t’ Oluwa busi. Ki ero at’ ope wan de Bi ebo turari s’orun K’
Read hymn : OJO mefa t’ ise kojaOJO oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su. Okunkun bo ile, Awon ‘rawo yo; Eranko at’ eiye, Lo si ‘busun won. Jesu f’ oru
Read hymn : OJO oni lo tanOJO ‘dajo, ojo, eru! Gbo bi ipe tin dun to! O ju egbarun ara lo, O sin mi gbogbo aiye. Bi esun na Yio ti damu elese. Wo Onidajo l’ awo wa,
Read hymn : OJO ‘dajo, ojo, eruOJO ‘mole l’ eyi, K’ imole wa l’oni; ‘Wo, Orun, ran s’ okunkun wa, K’o si le oru lo. Ojo ‘simi l’eyi, S’ agbara wa d’ otun; S’ ori aibale a
Read hymn : OJO ‘mole l’ eyiOJO ‘simi at’ ayo Ojo inu didun, Etutu fun wahala, T’ o dara, t’ o si ndan! L’ ori re, awon ‘lola At’ otosi nkorin, Pe, “Mimo, mimo, mimo,”
Read hymn : OJO ‘simi at’ ayoOJU ko ti ri, eti ko ti gbo Ese t’ Olugbala pa f’ enia Re, Awon ti O feran, tin won feran Re, Ti nwon nfi ayo sin ninu ile Re. B’ orun ti d
Read hymn : OJU ko ti ri, eti ko ti gboOJ’ oni lo Jesu Baba, Boju Re w’ emi omo Re. ‘Wo Imole, Se ‘toju mi; Tan imole Re yi mi ka. Olugbala, Nko ni beru, Nitori o Wa lodo mi. N
Read hymn : OJ’ oni loOKAN apata tuba, K’ eje Jesu mu o ro: Wo ara Re ti a gun, Wo bi eje ti bo O, Elese, kil’ o se yi? O kan mo agbelebu. Loto, ese re lo se, L’
Read hymn : OKAN apata tubaOKAN are, ile kan mbe, Jina rere s’ aiye ise; Ile t’ ayida ko le de, Tani fe lo simi nibe? Duro…. roju duro, mase kun!: Duro, duro, sa roju,
Read hymn : OKAN are, ile kan mbeOKAN mi nsimi, Oluwa; Ngo dupe, ngo ko ‘rin, Okan mi r’ ibi asiri Ti ire ti nsun wa. Mo k’ ongbe orison iye, O se yo l’ ara Re; Mo wa isura
Read hymn : OKAN mi nsimi, OluwaOKAN mi pe ninu Jesu: Ko beru ise ofin mo; Erin Olorun dun ninu, Nibit’ o ti kun f’ ese ri. Okan mi ye ninu Jesu; O gb’ alafia ‘dariji Re;
Read hymn : OKAN mi pe ninu JesuOKAN mi yin Oba orun, Mu ore wa sodo Re; ‘Wo t’ a wo san, t’ a dariji, Tal’ a ba ha yin bi Re? Yin Oluwa, Yin Oba ainipekun. Yin, fun anu t
Read hymn : OKAN mi yin Oba orunOKAN mi, odun kan ninu Aiye re koja lo; Eni ko le gbe ihin pe, Eyi le j’ opin mi. Ji okan mi, f’ opo suru Be iduro re wo; Kini ohun t’ o gb
Read hymn : OKAN mi, odun kan ninu