NIHIN l’ awa nje ‘rora
NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to! Dun to, dun to, dun to! A! bi yio ti dun to! Gbat’ a
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘rora643 hymns
NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to! Dun to, dun to, dun to! A! bi yio ti dun to! Gbat’ a
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘roraNIHIN l’ ayida wa, Ojo, erun nkoja; Ile ni nyan, ti o si nsa, ‘Tana dada si nku; Sugbon oro Jesu duro, “Ngo wa pelu re” ni On wi. Nihin l’
Read hymn : NIHIN l’ ayida waNIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han. Opo igba mi l’ o sofo, Be boya mo sun
Read hymn : NIHIN l’ Olorun sin mi deNIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile. Ewu on ‘banuje Wa yi mi kakiri; Orun ni ilu mi, Orun n’ ile. Bi iji tile nj
Read hymn : NIHIN mo j’ alejoNIHIN, l’ oko Re Oluwa, A ko ‘le ‘rupe yi fun O, Yan fun ‘bugbe Re Pataki, K’ O si so lowo asise. Gb’ enia Re ba nwa O nihin, T’ elese mbeb
Read hymn : NIHIN, l’ oko Re OluwaNIHINYI n’ isimi gbe wa, N’iha Re t’ eje nsan; Eyi nikan n’ ireti mi, Pe Jesu ku fun mi. Olugbala, Olorun mi, Orison f’ ese mi; Ma f’ eje R
Read hymn : NIHINYI n’ isimi gbe waNINU gbogbo ewu oru, Oluwa l’ O nso wa; A wa tun ri imole yi, A tun tee kun ba. Oluwa pa wa mo loni, Fi apa Re so wa, Kiki awon t’ Iwo pamo
Read hymn : NINU gbogbo ewu oruNINU gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi ‘ponju, Abo kan mbe ti o daju, O wa labe ite-anu Ibi kan wa ti Jesu nda Ororo ayo s’ ori wa; O dun
Read hymn : NINU gbogbo iji ti njaNINU oru ibanuje, L’ awon egbe ero ayo, Nwon nkorin ‘reti at’ ayo, Nwon nlo s’ ile ileri. Niwaju wa nin’ okunkun, Ni imole didan ntan, Awon
Read hymn : NINU oru ibanujeNIPA ife Olugbala, Ki y’o si nkan; Oju rere Re ki pada. Ki y’o si nkan. Owon l’eje t’o wo wa san, Pipe l’edidi or’-ofe, Agbara l’owo t’o gba
Read hymn : NIPA ife OlugbalaNIWAJU ite anu Re, Jesu, a tun ko ‘ra wa de, A wa toro idariji, Fun majemu t’ a ti baje. A wa se otun ileri, Ipa Re l’ o o le di wa mu, Lat
Read hymn : NIWAJU ite anu ReNIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun. Ipa Re laisi ‘ranwo wa, L’ O famo da wa l’
Read hymn : NIWAJU ‘te Jehofa nlaNJ’ Onidajo yio wa? Nj’ oku yio ji dide? Nje ko s’ eniti yio le sa Kuro ni oju Re? Ba’o l’ okan mi yio ti Gba eru ojo na, Nigbat’ orun ati
Read hymn : NJ’ Onidajo yio waNKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘le, Ko tun si ona miran; Nko le ri ilekun imole na Bi nko si l’ ona agbelebu. S’ ile l’ on’ agbelebu, S’ il
Read hymn : NKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘leNWON duro fun ete kan Nwon gbo t’Olorun; Bola fun Olotito K’a nyin egbe Daniel – Ki a se bi Daniel, K’a fi igboya Pa ete otito kan T’o ma h
Read hymn : NWON duro fun ete kanN’IFE l’ a te ona T’ Olugbala ti rin; A f’ apere Olori wa, Agutan Olorun. Li are Re nikan N’ ireti war o mo, Iwo t’ O s’ etutu f’ ese, T’ O
Read hymn : N’IFE l’ a te onaN’NU ‘se, n’nu ‘ja, Oluwa mi, Ngo rin li ona Re; B’ Iwo ti se l’ emi o se, Nipa iranwo Re. Pelu ‘tara, ayo l’o fi Se ife Baba Re; Itara na
Read hymn : N’NU ‘se, n’nu ‘ja, Oluwa miO FUN mi l’ edidi, ‘Gbese nla ti mo je; B’ O ti fun mi, O si rerin Pe, “Mase gbegbe Mi!” O fun mi l’ edidi, O san igbese na, B’ o ti fun mi
Read hymn : O FUN mi l’ edidiO HA le je p’ a mi? Olugbala ha yan mi? Bi ebi mi tip o to O ha da oruko mi? Olor’ elese ni mi Mo ha je n’ ireti be? A ha pe mi? O ya mi, N
Read hymn : O HA le je p’ a mi“O SUN,” ni Jesu wi Nipa ti Lasaru, Enit’ o ku, ti a ti san, T’ a ti te s’ iboji. Oku ojo merin, L’ oju Jesu, sun ni, On l’ Ajinde ati Iye
Read hymn : O SUN,” ni Jesu wiO TI to Jesu f’ agbara ‘wenumo? A we o nin’ ej Odagutan? Iwo ha ngbekele ore-ofe Re? A we o nin’ ej Odagutan? A we o? Nin eje Nin’ ej’ Odag
Read hymn : O TI to Jesu f’ agbara ‘wenumoOBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘se On la mu wa fi sun niwaju Jesu; Jesu terire ba. O nkowe n’ ile; T’ agba t’ ewe nf’ obirin yi seleya. We mi,
Read hymn : OBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘seODE, Kristi Oluwa, Lat’ ibugbe Re l’ orun, Lat’ ite alafia. O wa si aginju wa. Alade Alana De, lati ru ‘ponju wa; O de, lati f’ imole, Le o
Read hymn : ODE, Kristi OluwaODODO Re nikan laise t’ emi, L’ o le se isimi fun okan mi; Ife Re l’ o le mu k’ ifoiya lo, L’ o le da iji okan mi l’ ekun. Agbelebu wipe if
Read hymn : ODODO Re nikan laise t’ emi