MASE huwa ese
MASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa. Krist je oninure, At’ eni mimo; Be l’ awon omo Re Ye k’ o je mimo. Emi ibi kan wa
Read hymn : MASE huwa ese643 hymns
MASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa. Krist je oninure, At’ eni mimo; Be l’ awon omo Re Ye k’ o je mimo. Emi ibi kan wa
Read hymn : MASE huwa eseMIMO, mimo, mimo! Olodumare! Ni kutukutu n’Iwo o gbo orin wa; Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo! Ologo meta lai, Olubukun! Mimo, mimo, mimo! A
Read hymn : MIMO, mimo, mimo! Olodumare!mJE k’ agb’ oju ayo s’ oke Si agbala orun, K’ a yo lati ri Baba wa Lori ite ife. Wa, je k’ a wole l’ ese Re, K’ a sunmo Oluwa, Angeli ina t
Read hymn : mJE k’ agb’ oju ayo s’ okeMO duro de Olorun mi, O si gbo igbe mi, O ri mo simi l’ oro Re, O si mu ‘gbala wa. O yo mi l’ ogbun okunkun, Nibiti mo ns’ ofo, O si yo ese
Read hymn : MO duro de Olorun miMO fe gbo itan kanna T’ awon Angeli-nso; Bi Oba Ogo ti wa, Gbe aiye osi yi; Bi mo tile j’ elese, Mo mo eyi daju, Pe Oluwa wa gba mi, ‘Tori O
Read hymn : MO fe gbo itan kannaMO fe iyera s’ apakan Kuro l’ ero t’ aiye, Ki nf’ akoko iwo orun Kunle gba adura. Mo few a nikan ki nsokun Ti irobinuje, N’ iyewu kin ran O
Read hymn : MO fe iyera s’ apakanMO fe ki ndabi Jesu, Ninu iwa pele; Ko s’ enit’ o gboro ‘binu L’ enu Re lekan ri. Mo fe ki ndabi Jesu, L’ adura ‘gbagbogbo; Lori oke ni On
Read hymn : MO fe ki ndabi JesuMO Fe mo nipa Jesu sii, F’or’ ofe Re h’ elomiran; Ki nle ri ‘gbala kikun Re, Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi. Ki nmo nipa Jesu sii, Ki nmo ni
Read hymn : MO Fe mo nipa Jesu siiMO fe O n’gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s’ ohun ti nfun ni L’ alafia bi Tire Mo fe O, a! mo fe O, Ni wakati gbogbo; Bukun mi Olugbala, Mo wa s’
Read hymn : MO fe O n’gbagbogbo,MO fe O, Olorun, sugbon Ki se fun ere kan, Ki se nitori’ eniti Ko ba fe O yio ku, Mo fe O, Olorun, sibe Ngo ma fe O titi; ‘Torip’ Olorun mi
Read hymn : MO fe O, Olorun, sugbonMO feran iwe oro Re; O f’ imole at’ ayo fun Okan okun on ‘banuje! Oro Re t’ oan mi wiwo; Eru Re ko jeki nsirin, ‘Leri Re m’ okan mi simi. E
Read hymn : MO feran iwe oro ReMO fi gbogbo re fun Jesu Patapata laiku kan; Ngo ma fe ngo si gbekele, Ngo si ma ba gbe titi. Mo fi gbogbo re, Mo fi gbogbo re, Fun O Olugb
Read hymn : MO fi gbogbo re fun JesuMO fi omije wo yika, Aiye su bi iji okun; Sibe, larin re, mo gb’ ohun, O nwi, je pe, “Wa sodo Mi!” O nso t’ ibi ayo fun mi, T’ ibit’ okan m
Read hymn : MO fi omije wo yikaMO f’ ara Mi fun o, Mo ku nitori re, Ki nle ra o pada, K’ o le jinde n’nu ‘ oku; Mo f’ ara Mi fun o, Kin’ iwo se fun Mi? Mo f’ ojo aiye Mi
Read hymn : MO f’ ara Mi fun oMO gbeke mi le O, Lori ibusun mi, Gba mi lowo irora mi, Ki O si wo mi san. Ko s’ elomiran mo, Ti mo tun gbekele, O san fun ‘ya aya Pita, Ni
Read hymn : MO gbeke mi le OMO gbohun Jesu t’ o wipe, “Wa simi lodo Mi; Gbe ori re, ‘wo alare, Le okan aiya Mi.” Ninu are on ‘banuje, Ni mo to Jesu wa; O je ib’ isimi f
Read hymn : MO gbohun Jesu t’ o wipeMO ha le tun duro Laif’ ini mi toro? Ki nmu okan kuro l’ aiye, Ki ngba Olugbala? Beko, mo ti tuba, Nko le ba du lo pe, Iku ife mu mi n’ ipa
Read hymn : MO ha le tun duroMO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajeji, Ile mi jin rere, l’or’ ebute wura; Lati je iranse n’koja okun l’ohun, Mo nsise nihin f’ oba mi Eyi ni ‘se
Read hymn : MO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajejiMO korin ipa Olorun, T’ O gbe oke dide, T’ O tan odo tin san kiri, T’ O si k’ orun giga. Mo korin ogbon t’ o mu ki Orun ko ran l’ osan Osup
Read hymn : MO korin ipa OlorunMO k’ ese mi le Jesu, Od’ agutan mimo; O ru gbogbo eru mi, O so mi d’ominira; Mo rue bi mi to wa K’Owe eri minu. K’eje Re iyebiye Le so mi d
Read hymn : MO k’ ese mi le Jesu“MO mo p’Oludande mi mbe;” Itunu nla l’eyi fun mi! O mbe, Enit’ o ku lekan; O mbe, Ori iye mi lai. O mbe, lati ma bukun mi, O si mbebe fun
Read hymn : MO mo p’Oludande mi mbeMO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo, On na ko ko ni bi ore aiye sa; Tifetife li on nse ajo lori mi, Mo fe k’ Olugbala mi si je tire. Fun o m
Read hymn : MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogoMO n’ ‘ore, kan, A, Ore na! N’ ife mi k’ emi to mo, On f’ okun ife Re nla, Fa mi sunmo odo Re, Ka okan mi n’ ife nla na N’ ide ti nkan ko le
Read hymn : MO n’ ‘ore, kan, A, Ore naMO ti mb’ese rin ti pe, Pin wa n’iya, Oluwa, Ore’parun ni tire, Gba mi Jesu, mo segbe. ko s’ anfani ti mo ri L’ ara ati l’ okan mi, Gbogbo
Read hymn : MO ti mb’ese rin ti pe