MO ti ni Jesu l’ore
MO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado; On ni enikan na T’o le we mi nu kuro nin’es
Read hymn : MO ti ni Jesu l’ore643 hymns
MO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado; On ni enikan na T’o le we mi nu kuro nin’es
Read hymn : MO ti ni Jesu l’oreMO ti se ‘leri, Jesu, Lati sin O d’ opin; Ma wa lodo mi titi, Baba mi, Ore mi, Emi k’ y’o beru ogun, B’ Iwo ba sunmo mi, Emi ki y’o si sina,
Read hymn : MO ti se ‘leri, JesuMO yo pipo pe Baba wa orun So t’ife Re ninu ‘we t’o fun mi, Mo r’ ohun ‘yanu ninu Bibeli, Eyi sowon ju pe Jesu fe mi, Mo yo pipo pe Jesu fe
Read hymn : MO yo pipo pe Baba wa orunMOKANDILOGORUN dubule je, Labe oji nin’ agbo; Sugbon okan je lo s’ or’ oke, Jina s’ ilekun wura; Jina rere lor’ oke sisa, Jina rere s’ Olus’
Read hymn : MOKANDILOGORUN dubule jeMURA ebe, okan mi Jesu nfe gb’ adura re; O tip e k’ o gbadura, Nitorina yio gbo. Lodo Oba n’ iwo mbo, Wa lopolopo ebe; Be l’ ore-ofe Re po,
Read hymn : MURA ebe, okan miMURA elese lati gbon, Ma duro de ojo ola; Niwon b’ o ti kegan ogbon, Be l’ o si soro lati ri. Mura lati bere anu, Ma duro de ojo ola; Ki ig
Read hymn : MURA elese lati gbonNAIJIRIA, a ki o, Orile wa owon Eya, ede le yato A duro ni ‘sokan, Pelu ayo l’a o sin O Ile t’a gbe bi wa. Asia wa yio j’ ami, Pe eto lo nj
Read hymn : NAIJIRIA, a ki oNGO fe O, Olorun Baba, Olugbala, Oba mi; Ngo fe O, ‘tori laisi Re Aiye j’ ohun kikoro. Ngo fe O, gbogbo ibukun Nsan lat’ ife Re si mi; Ngo
Read hymn : NGO fe O, Olorun BabaNGO feran Re, Wo odi mi; Ngo feran Re, ‘Wo ayo mi; Ngo feran Re, patapata; Ngo feran Re, tor’ ise Re, Ngo feran Re, tit’ okan mi, Y’o fi kun
Read hymn : NGO feran Re, Wo odi miNGO ha ku ni owo ofo, Ki mba oluwa mi be Ko ti fun u n’ise ojo kan, Ikogun fun On ko si. Ngo ha ku ni owo ofo Ngo ha r’ Oluwa mi be Ko si e
Read hymn : NGO ha ku ni owo ofoNGO je ‘mole fun Jesu, Ki ntan nigba gbogbo, Ki ntan s’ ibi to fe mi, Ki ntan l’ojojumo, L’ oro ‘fe ati n’ ise, Lo mi Oluwa mi; Ki ntun ‘le
Read hymn : NGO je ‘mole fun JesuNGO korin itan ‘yanu na, Ti Jesu t’ o ku fun mi, B’ On ti fi ‘le ogo sile, F’agbelebu Kalfari. A ngo korin tan ‘yanu na – Ti Jesu t’ o ku f
Read hymn : NGO korin itan ‘yanu naNGO sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O; B’ o tile se ‘ponju, L’ o mu mi wa; Sibe orin mi je, Ngo sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O, Ni ona ajo mi, B’
Read hymn : NGO sunm’ O, OlorunNI akoko ipinya, Jeki a fi ara wa, S’ abe oju at’ okan, Ore korikosun wa. Jesu gbo adura wa, ‘Wo ti nso agutan K’ anu at’ itoju Re, Pa gbog
Read hymn : NI akoko ipinyaNI Kanani ti Galili, Nib’ ase ‘gbeyawo, Jesu f’ ara Re han nibe, Pel’ awon ‘mo-ehin. Jesu masai f’ ara Re han Nibi ‘gbeyawo yi, K’ O si fi
Read hymn : NI Kanani ti GaliliNI kutu, mo de Oluwa Lati wa oju Re, Okan ongbe mi da ‘ku lo, Lais’ ayo ore Re. B’ o ti wu ki ase dun to, Ko le te mi l’ orun; B’ igba mo n
Read hymn : NI kutu, mo de OluwaNIBO n’ isimi wa Fun okan alare? Asan ni lati w’ aiye ka, Lati wa ‘le okun. Aiye ko le fun ni Layo t’ a nkedun fun; Igba ko tan aiyeraiye,
Read hymn : NIBO n’ isimi waNIGBA igbi aiye ba dide si o, T’ okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y’o ya o fun nkan t’ Oluwa t’se. Ro
Read hymn : NIGBA igbi aiye ba dide si oNIGBA itiju k obo mi, Mo f’ eru sa b’ agbelebu; Pelu eru ebi lori, Ife fa mi, mo bo ‘waju, Mo r’ anu at’ alafia, Nipa eje Jesu Kikun. Ese m
Read hymn : NIGBA itiju k obo miNIGBA nwon kehin si Sion, A! opo n’ iye won; Mo seb’ Olugbala wipe, ‘Wo fe ko mi pelu? T’ emi t’ okan b’ iru eyi A fi b’ O di mi mu; Nko le
Read hymn : NIGBA nwon kehin si SionNIGBAKAN ni Betlehemu Ile kekere kan wa; Nib’ iya kan te ‘mo re si Lori ibuje eran; Maria n’ iya Omo na, Jesu Kristi l’ Omo na. O t’ orun w
Read hymn : NIGBAKAN ni BetlehemuNIGBAT’ idanwo yi mi ka, T’ idamu aiye mu mi, Ti Esu wa bi ore mi, Lati wa iparun mi. Oluwa, jo masai pe mi, B’ O ti p’ Adam n’nu ogba, Pe,
Read hymn : NIGBAT’ idanwo yi mi kaNIGBAT’ imole owuro Ba nti ila orun tan wa, A! Orun ododo mimo Ma sai fi anu ran si mi! Tu isudede ebi ka S’ okunkun mi d’ imole nla. Gbat
Read hymn : NIGBAT’ imole owuroNIGBAT’ ipe ba dun, Ngo dide n’nu ‘boji, Ngo r’ Onidajo Alade, Ri sanma t’ o ngbina. Pel’ ayo tab’ ekun, Ni ngo f’ iboji ‘le, Kini yio pade
Read hymn : NIGBAT’ ipe ba dun