LAT’ ori pepe okan wa
LAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa. Iseju at’ opo anu L’ a fi s’ ojo oni, Iseju nfo, sugbon anu, O
Read hymn : LAT’ ori pepe okan wa643 hymns
LAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa. Iseju at’ opo anu L’ a fi s’ ojo oni, Iseju nfo, sugbon anu, O
Read hymn : LAT’ ori pepe okan waLEHIN aiye buburu yi, Aiye ekun on osi yi, Ibi rere kan wa, Ayipada ko si nibe? Ko s’ oru, af’ osan titi, Wi mi, ‘wo o wa nibe? ‘Lekun ogo
Read hymn : LEHIN aiye buburu yiLEHIN odun die, Lehin igba die, A o ko wa jo pel’ awon Ti o sun n’ iboji. Jesu Oluwa mi! Mu mi mura de O; Jo we mi ninu eje Re, Si ko ese mi
Read hymn : LEHIN odun dieLEHIN ‘jo mefa t’ O sise, O simi ni ijo keje, O pase fun wa k’ a se be, Ki a si pa ojo na mo. A wa lati m’ ase na se, Ninu ile Re yi loni,
Read hymn : LEHIN ‘jo mefa t’ O siseLI o wuro Iwo o gbo Ohun mi, Oluwa; S’ odo Re l’ emi o dari Oju adura mi. Si oke ti Jesu lo be Fun awon enia Re; Ti o fi irahun wa han Baba
Read hymn : LI o wuro Iwo o gboLO kede igbala Jesu Gbogbo enyin onigbagbo Fun ‘rugbin Sharon ka gbogbo, Orile ede aiye yi. Yio f’ agbala ‘na yi o ka Yio f’ itara kun okan
Read hymn : LO kede igbala Jesu“LO wasu Mi,” l’ Oluwa wi: Wi f’ aiye k’ o gba ore Mi; Enit’ o gb’ oro Mi y’o la, En’ti ko gbagbo y’o segbe. “Ngo jek’ a mo ase nyin nla, E
Read hymn : LO wasu Mi,” l’ Oluwa wiLO, l’ oro kutu kutu, Lo, ni osangangan, Lo, ni igba asale, Lo l’ oganjo oru; Lo, t’ iwo t’ inu rere, Gbagbe ohun aiye, Si kunle n’ iyewu re
Read hymn : LO, l’ oro kutu kutuLODO Re sibe nigbat’ ojumo mo, Ti awon eiye ji, ti kuku lo: Rekoja t’ orun ni didan imole, Idaloju pe, “O wa lodo mi.” Nigbati are mu okan
Read hymn : LODO Re sibe nigbat’ ojumo moLONI ni Jesu pe! Asako wa; A! okan okunkun Ma kiri mo. Loni ni Jesu pe, Tetilele: Ni ile owo yi, Wole, Jesu. Loni ni Jesu pe! Sa asala: Ij
Read hymn : LONI ni Jesu peL’ AYO l’ a ro t’ ore-ofe Alufa wa l’ oke; Okan Re kun fun iyonu, Aiya Re ntan fun ‘fe. Nipa ibakedun okan, O mo ailera wa; O mo ohun t’ id
Read hymn : L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofeL’ OJU ale, ‘gbat’ orun wo, Nwon gbe abirun wodo Re: Oniruru ni aisan won, Sugbon nwon f’ayo lo le won Jesu a de loj’ ale yi, A sunmo, t’aw
Read hymn : L’ OJU ale, ‘gbat’ orun woL’ONA gbogbo t’ Oluwa yan, Ajo mi l’ emi o to; Ma da mi ro, eyin mimo, Emi o ban yin lo. Bi Jesu nlo ninu ina, Emi o to lehin; Ma da mi ro
Read hymn : L’ONA gbogbo t’ Oluwa yanL’OWURO, Ojo ajinde, T’ara t’okan y’o pade, Ekun, ‘kanu on irora Y’o d’opin. Nihin nwon ko le sai pinya, Ki ara ba le simi, K’o si fi idake
Read hymn : L’OWURO, Ojo ajindeMA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni Isegun kan yio f’ ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja ‘Bere k’
Read hymn : MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese niMA gesin lo l’ olanla Re; Gbo, gbogb’ aiye nke “Hosanna”, Olugbala ma lo pele Lori ‘m’ ope at aso. Ma gesin lo l’ olanla Re; Ma f’ irele ge
Read hymn : MA gesin lo l’ olanla ReMA koja mi, Olugbala, Gbo adura mi; ‘Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja mi! Jesu! Jesu! Gbo adura mi, Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja
Read hymn : MA koja mi, OlugbalaMA sise lo, mase sare, Fi ayo sise Baba re; Bayi ni Jesu se l’ aiye Ko ha ye k’ awa ko se be? Ma sise lo, l’ ojojumo, Okunkun aiye fere de;
Read hymn : MA sise lo, mase sareMA so fun mi l’ ohun aro Pe iye dabi ala; Okan ti ntogbe li o ku, ‘Kan ko ri bi a ti nro. Iye mbe se! Iye mbe se! ‘Boji ki si s’ opin re; K
Read hymn : MA so fun mi l’ ohun aroMA so ra, okan mi, A won ota dide; Ogun ese si mura tan, Lati fa o lu ‘le. Ma ja, ma gbadura, Mase so ‘reti nu; Bere l’ otun l’ ojojumo, To
Read hymn : MA so ra, okan miMA sun lo, olufe; sa ma simi, F’ ori re le aiya Olugbala; A fe o, sugbon Jesu fe o ju:- O di owuro o! Orun re dun bi orun omode, B’ o si ji
Read hymn : MA sun lo, olufe; sa ma simiMA toju, Jehofah nla, Ero l’ aiye osi yi, Emi ko l’ okun, iwo ni, F’ ow’ agbara di mi mu, Onje orun, Ma bo mi titi lailai. S’ ilekun isun o
Read hymn : MA toju, Jehofah nlaMA wo ‘le, Jesu t’ a nreti, T’a bi lati gba ni la! Gba wa low’ ese at’ eru, K’ a r’ isimi ninu Re. Ipa at’ itunu Israel; Ireti awon mimo; O
Read hymn : MA wo ‘le, Jesu t’ a nretiMASE f’oiya ohun t’ o le de, Olorun y’o so o; Duro labe iye Re, Olorun y’o so o. Olorun y’o so o, Lojo gbogbo l’ ona gbogbo; On y’o ma toju
Read hymn : MASE f’oiya ohun t’ o le de