MA so ra, okan mi
MA so ra, okan mi, A won ota dide; Ogun ese si mura tan, Lati fa o lu ‘le.
Read hymn : MA so ra, okan miMA so ra, okan mi, A won ota dide; Ogun ese si mura tan, Lati fa o lu ‘le.
Read hymn : MA so ra, okan miJESU wipe k’ a ma sora Ni wakati gbogbo, O si nf’ emi isoji fun Awon t’ o mbere re.
Read hymn : JESU wipe k’ a ma soraOKAN wa ji; k’ eru fo lo, Ki gbogbo ifoiya k’o lo; Ji, k’ o sis are ‘je orun, Si fi igboiya ayo han.
Read hymn : OKAN wa ji; k’ eru fo loOM’-OGUN Krist’ dide Mu ‘hamora nyin wo; Mu ‘pa t’ Olorun fi fun nyin, Nipa ti Omo Re.
Read hymn : OM’-OGUN Krist’ dide.EMA te siwaju, Kristian ologun, Ma tejumo Jesu t’ O mbe niwaju Kristi Oluwa wa ni Balogun wa, Wo! asia Re wa niwaju ogun;
Read hymn : EMA te siwaju, Kristian ologunHA! egbe mi, e w’ asia Bi ti nfe lele Ogun Jesu fee de na, A fere segun!
Read hymn : HA! egbe mi, e w’ asiaKRISTIAN ma ti wa ‘simi, Beli angeli re nwi, Ni arin ota l’ owa, Ma sora.
Read hymn : KRISTIAN ma ti wa ‘simi,DURO, duro fun Jesu, Enyin om’ogun Krist’: Gbe asia Re s’ oke, A ko gbodo fe ku;
Read hymn : DURO, duro fun Jesu,BABA orun, nin’ oro Re Ni ogo orun ntan; Titi lai l’ a o ma sin O, Fun Bibeli mimo.
Read hymn : BABA orun, nin’ oro ReA, JEKI oro mimo Re Fi agbara si okan mi, F’ imole at’ ife orun Wi f’ okan mi pe, “Wo t’ emi.”
Read hymn : A, JEKI oro mimo ReBIBELI mimo t’ orun Owon isura t’ emi! ‘Wo ti nwi bi mo ti ri, ‘Wo ti nso bi mo ti wa.
Read hymn : BIBELI mimo t’ orunBABA orun, ti ife Re B’ okan wa, wa irapada, A teriba niwaju Re, Jo fun wa n’ idariji Re.
Read hymn : BABA orun, ti ife Re