L’ONA gbogbo t’ Oluwa yan
L’ONA gbogbo t’ Oluwa yan, Ajo mi l’ emi o to; Ma da mi ro, eyin mimo, Emi o ban yin lo.
Read hymn : L’ONA gbogbo t’ Oluwa yan643 hymns
L’ONA gbogbo t’ Oluwa yan, Ajo mi l’ emi o to; Ma da mi ro, eyin mimo, Emi o ban yin lo.
Read hymn : L’ONA gbogbo t’ Oluwa yanL’OWURO, Ojo ajinde, T’ara t’okan y’o pade, Ekun, ‘kanu on irora Y’o d’opin.
Read hymn : L’OWURO, Ojo ajindeMA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni Isegun kan yio f’ ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja
Read hymn : MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese niMA gesin lo l’ olanla Re; Gbo, gbogb’ aiye nke “Hosanna”, Olugbala ma lo pele Lori ‘m’ ope at aso.
Read hymn : MA gesin lo l’ olanla ReMA koja mi, Olugbala, Gbo adura mi; ‘Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja mi!
Read hymn : MA koja mi, OlugbalaMA sise lo, mase sare, Fi ayo sise Baba re; Bayi ni Jesu se l’ aiye Ko ha ye k’ awa ko se be?
Read hymn : MA sise lo, mase sareMA so fun mi l’ ohun aro Pe iye dabi ala; Okan ti ntogbe li o ku, ‘Kan ko ri bi a ti nro.
Read hymn : MA so fun mi l’ ohun aroMA so ra, okan mi, A won ota dide; Ogun ese si mura tan, Lati fa o lu ‘le.
Read hymn : MA so ra, okan miMA sun lo, olufe; sa ma simi, F’ ori re le aiya Olugbala; A fe o, sugbon Jesu fe o ju:- O di owuro o!
Read hymn : MA sun lo, olufe; sa ma simiMA toju, Jehofah nla, Ero l’ aiye osi yi, Emi ko l’ okun, iwo ni, F’ ow’ agbara di mi mu,
Read hymn : MA toju, Jehofah nlaMA wo ‘le, Jesu t’ a nreti, T’a bi lati gba ni la! Gba wa low’ ese at’ eru, K’ a r’ isimi ninu Re.
Read hymn : MA wo ‘le, Jesu t’ a nretiMASE f’oiya ohun t’ o le de, Olorun y’o so o; Duro labe iye Re, Olorun y’o so o.
Read hymn : MASE f’oiya ohun t’ o le de