GBO ase ti Jesu pa
GBO ase ti Jesu pa, “Lo wasu ‘hinrere Mi, Enikeni t’ o gbagbo, T’ a si tebomi, yio la.”
Read hymn : GBO ase ti Jesu paGBO ase ti Jesu pa, “Lo wasu ‘hinrere Mi, Enikeni t’ o gbagbo, T’ a si tebomi, yio la.”
Read hymn : GBO ase ti Jesu paGBO ohun t’ o dun lat’ oke Si Jesu l’ odo Jordani, Eri fun gbogbo araiye, “Eyi l’ ayanfe Omo Mi.”
Read hymn : GBO ohun t’ o dun lat’ okeELESE, nipa ‘jewo re Si itiju Jesu, Si irora at’ iku Re Lori agbelebu.
Read hymn : ELESE, nipa ‘jewo reWO, awon t’ o ‘so ala, Nwon duro leti odo, Nwon k’ ehin s’ aiye at’ esu, Nwon ntele Atebomi;
Read hymn : WO, awon t’ o ‘so alaOHUN tin dun l’ aginju, Ohun alore ni, Gbo b’ o tin dun rara pe, “E ronupiwada.”
Read hymn : OHUN tin dun l’ aginjuJESU Or’ elese mo de, Em’ otosi wa fun ‘rawo, Ara mi su mi fun ese, Na apa Re gba mi s’ ile.
Read hymn : JESU Or’ elese mo deMO yo pipo pe Baba wa orun So t’ife Re ninu ‘we t’o fun mi, Mo r’ ohun ‘yanu ninu Bibeli, Eyi sowon ju pe Jesu fe mi,
Read hymn : MO yo pipo pe Baba wa orunWA ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu nisin! Nisin wa’ do Jesu!
Read hymn : WA ‘do Jesu!JESU np’ enia Re S’ ori tabili Re, Nibi l’ awon t’ a dariji Nb’ Oluwa won dapo.
Read hymn : JESU np’ enia ReIFE orun! alailegbe! N’nu ase mimo yi, Ogo re kun, ‘mole re po, Ti ntan iye jade.
Read hymn : IFE orun! alailegbeJESU t’ asia Re bow a, O f’ onje m’ okan way o; O te ase siwaju wa, T’ a f’ eran ara Re se.
Read hymn : JESU t’ asia Re bow aGBATI mo ri agbelebu, Ti a kan Oba-ogo mo, Mo ka gbogbo oro s’ ofo, Mo kegan gbogbo ogo mi.
Read hymn : GBATI mo ri agbelebu,