OLORUN ‘kore, te ‘ti Re
OLORUN ‘kore, te ‘ti Re, F’ ara Re han l’ ogun Sion; Ran ojise t’ o n’ itara, T’ o yara lati gb’ ase Re.
Read hymn : OLORUN ‘kore, te ‘ti ReOLORUN ‘kore, te ‘ti Re, F’ ara Re han l’ ogun Sion; Ran ojise t’ o n’ itara, T’ o yara lati gb’ ase Re.
Read hymn : OLORUN ‘kore, te ‘ti ReIJINLE l’ oro Re, Jesu, Tani le tumo re? Tani gbon to! tani mo to! Tal’ oye re po to!
Read hymn : IJINLE l’ oro Re, JesuOWO l’ eni ororo Re, L’ ojise oro mimo Re Ipo eni owo l’ o wa, Jek a f’ iyin at’ ola fun.
Read hymn : OWO l’ eni ororo ReKRIST’, nin’ ogba Eden, L’ a gbe ti ri r’ ase yi, Ase Tire, P’ o ye f’ eni meji
Read hymn : KRIST’, nin’ ogba EdenNI Kanani ti Galili, Nib’ ase ‘gbeyawo, Jesu f’ ara Re han nibe, Pel’ awon ‘mo-ehin.
Read hymn : NI Kanani ti GaliliIRE t’ a su ni Eden’, N’ igbeyawo ‘kini, Ibukun t’ a bukun won O wa sibesibe.
Read hymn : IRE t’ a su ni EdenJESU f’ ara han nitoto, Nibi ase ‘yawo; Oluwa, awa be O, wa F’ ara re han nihin.
Read hymn : JESU f’ ara han nitotoSIMI le Oluwa -e gbo Orin duru orun – Simi le ife ailopin, Si duro je,
Read hymn : SIMI le Oluwa -e gboJESU f’ eje Re raw a, E jek’ a sunm’ Olorun; Opo nsina yi wa ka; K’ anu mu wag badura, –
Read hymn : JESU f’ eje Re raw aWA, Oluwa, l’ anu tun wa, Pelu ‘pa ‘p’ okan da, Ongbe ojo np’ oko Sion, Masai ro s’ ori re.
Read hymn : WA, Oluwa, l’ anu tun waGBO l’ or’ ite Re, Alade, F’ oniruru ‘bukun ranse, B’ awon omo Re ti nwa O, Gb’ adura t’ oro Re ko ni.
Read hymn : GBO l’ or’ ite Re, AladeOLUWA, mo gbo pe Iwo Nro ojo ‘bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s’ ori mi.
Read hymn : OLUWA, mo gbo pe Iwo