MO ti ni Jesu l’ore
MO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado;
Read hymn : MO ti ni Jesu l’ore643 hymns
MO ti ni Jesu l’ore, O j’ ohun gbogbo fun mi, On nikan l’arewa ti okan mi fe, On n’itanna ipado;
Read hymn : MO ti ni Jesu l’oreMO ti se ‘leri, Jesu, Lati sin O d’ opin; Ma wa lodo mi titi, Baba mi, Ore mi,
Read hymn : MO ti se ‘leri, JesuMO yo pipo pe Baba wa orun So t’ife Re ninu ‘we t’o fun mi, Mo r’ ohun ‘yanu ninu Bibeli, Eyi sowon ju pe Jesu fe mi,
Read hymn : MO yo pipo pe Baba wa orunMOKANDILOGORUN dubule je, Labe oji nin’ agbo; Sugbon okan je lo s’ or’ oke, Jina s’ ilekun wura;
Read hymn : MOKANDILOGORUN dubule jeMURA ebe, okan mi Jesu nfe gb’ adura re; O tip e k’ o gbadura, Nitorina yio gbo.
Read hymn : MURA ebe, okan miMURA elese lati gbon, Ma duro de ojo ola; Niwon b’ o ti kegan ogbon, Be l’ o si soro lati ri.
Read hymn : MURA elese lati gbonNAIJIRIA, a ki o, Orile wa owon Eya, ede le yato A duro ni ‘sokan,
Read hymn : NAIJIRIA, a ki oNGO fe O, Olorun Baba, Olugbala, Oba mi; Ngo fe O, ‘tori laisi Re Aiye j’ ohun kikoro.
Read hymn : NGO fe O, Olorun BabaNGO feran Re, Wo odi mi; Ngo feran Re, ‘Wo ayo mi; Ngo feran Re, patapata; Ngo feran Re, tor’ ise Re,
Read hymn : NGO feran Re, Wo odi miNGO ha ku ni owo ofo, Ki mba oluwa mi be Ko ti fun u n’ise ojo kan, Ikogun fun On ko si.
Read hymn : NGO ha ku ni owo ofoNGO je ‘mole fun Jesu, Ki ntan nigba gbogbo, Ki ntan s’ ibi to fe mi, Ki ntan l’ojojumo,
Read hymn : NGO je ‘mole fun JesuNGO korin itan ‘yanu na, Ti Jesu t’ o ku fun mi, B’ On ti fi ‘le ogo sile, F’agbelebu Kalfari.
Read hymn : NGO korin itan ‘yanu na