NIBO n’ isimi wa
NIBO n’ isimi wa Fun okan alare? Asan ni lati w’ aiye ka, Lati wa ‘le okun.
Read hymn : NIBO n’ isimi waNIBO n’ isimi wa Fun okan alare? Asan ni lati w’ aiye ka, Lati wa ‘le okun.
Read hymn : NIBO n’ isimi waNIGBA igbi aiye ba dide si o, T’ okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y’o ya o fun nkan t’ Oluwa t’se.
Read hymn : NIGBA igbi aiye ba dide si oNIGBA itiju k obo mi, Mo f’ eru sa b’ agbelebu; Pelu eru ebi lori, Ife fa mi, mo bo ‘waju,
Read hymn : NIGBA itiju k obo miNIGBAKAN ni Betlehemu Ile kekere kan wa; Nib’ iya kan te ‘mo re si Lori ibuje eran;
Read hymn : NIGBAKAN ni BetlehemuNIGBA nwon kehin si Sion, A! opo n’ iye won; Mo seb’ Olugbala wipe, ‘Wo fe ko mi pelu?
Read hymn : NIGBA nwon kehin si SionNIGBAT’ idanwo yi mi ka, T’ idamu aiye mu mi, Ti Esu wa bi ore mi, Lati wa iparun mi.
Read hymn : NIGBAT’ idanwo yi mi kaNIGBAT’ imole owuro Ba nti ila orun tan wa, A! Orun ododo mimo Ma sai fi anu ran si mi!
Read hymn : NIGBAT’ imole owuroNIGBAT’ ipe ba dun, Ngo dide n’nu ‘boji, Ngo r’ Onidajo Alade, Ri sanma t’ o ngbina.
Read hymn : NIGBAT’ ipe ba dunNIHIN, l’ oko Re Oluwa, A ko ‘le ‘rupe yi fun O, Yan fun ‘bugbe Re Pataki, K’ O si so lowo asise.
Read hymn : NIHIN, l’ oko Re OluwaNIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to!
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘roraNIHIN l’ ayida wa, Ojo, erun nkoja; Ile ni nyan, ti o si nsa, ‘Tana dada si nku;
Read hymn : NIHIN l’ ayida waNIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han.
Read hymn : NIHIN l’ Olorun sin mi de