NIHIN mo j’ alejo
NIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile.
Read hymn : NIHIN mo j’ alejoNIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile.
Read hymn : NIHIN mo j’ alejoNIHINYI n’ isimi gbe wa, N’iha Re t’ eje nsan; Eyi nikan n’ ireti mi, Pe Jesu ku fun mi.
Read hymn : NIHINYI n’ isimi gbe waNI Kanani ti Galili, Nib’ ase ‘gbeyawo, Jesu f’ ara Re han nibe, Pel’ awon ‘mo-ehin.
Read hymn : NI Kanani ti GaliliNI kutu, mo de Oluwa Lati wa oju Re, Okan ongbe mi da ‘ku lo, Lais’ ayo ore Re.
Read hymn : NI kutu, mo de OluwaNINU gbogbo ewu oru, Oluwa l’ O nso wa; A wa tun ri imole yi, A tun tee kun ba.
Read hymn : NINU gbogbo ewu oruNINU gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi ‘ponju, Abo kan mbe ti o daju, O wa labe ite-anu
Read hymn : NINU gbogbo iji ti njaNINU oru ibanuje, L’ awon egbe ero ayo, Nwon nkorin ‘reti at’ ayo, Nwon nlo s’ ile ileri.
Read hymn : NINU oru ibanujeNIPA ife Olugbala, Ki y’o si nkan; Oju rere Re ki pada. Ki y’o si nkan.
Read hymn : NIPA ife OlugbalaNIWAJU ite anu Re, Jesu, a tun ko ‘ra wa de, A wa toro idariji, Fun majemu t’ a ti baje.
Read hymn : NIWAJU ite anu ReNIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun.
Read hymn : NIWAJU ‘te Jehofa nlaNJ’ Onidajo yio wa? Nj’ oku yio ji dide? Nje ko s’ eniti yio le sa Kuro ni oju Re?
Read hymn : NJ’ Onidajo yio waNKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘le, Ko tun si ona miran; Nko le ri ilekun imole na Bi nko si l’ ona agbelebu.
Read hymn : NKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘le